Igbala okan

Igbala okan Igbagbo ninu oro olorun ni n muni la, agbara enia ko.

Aye atijo ti koja lo, aye titun ati igba titun lokan fun awon ayanfe otito ati ododo.Ki alaafia Oluwa jesu kristi maa wa...
13/07/2023

Aye atijo ti koja lo, aye titun ati igba titun lokan fun awon ayanfe otito ati ododo.
Ki alaafia Oluwa jesu kristi maa wa pelu yin nigba gbogbo amin ase edumare

OGO NI FUN OLORUN LOKE ORUN, ALAAFIA NI AYE FUN AWON ENIA TI ONI IFE INU RERE.
12/07/2023

OGO NI FUN OLORUN LOKE ORUN, ALAAFIA NI AYE FUN AWON ENIA TI ONI IFE INU RERE.

Ki alaafia oluwa wa pelu yin
08/05/2022

Ki alaafia oluwa wa pelu yin

Ki alaafia oluwa Jesu kristi, Ife mimo ti baba, ati idapo sokan ti emi mimo ki o maa wa pelu yin nigba gbogbo amin
06/05/2022

Ki alaafia oluwa Jesu kristi, Ife mimo ti baba, ati idapo sokan ti emi mimo ki o maa wa pelu yin nigba gbogbo amin

24/03/2022

Asiri oluwa wa pelu awon ti o nberu re, yio si fi won mo majemu re, nitori iberu oluwa ni ipilese ogbon. Ki alaafia olorun olodumare maa wa pelu yin nigba gbogbo amin.

Adresse

Kpedekpo
Cotonou
OLAOLUWA

Téléphone

+22966226675

Site Web

Notifications

Soyez le premier à savoir et laissez-nous vous envoyer un courriel lorsque Igbala okan publie des nouvelles et des promotions. Votre adresse e-mail ne sera pas utilisée à d'autres fins, et vous pouvez vous désabonner à tout moment.

Partager