Jesus is the Way and Salvation Evangelical Ministry - Jesus Itwasem

  • Home
  • Nigeria
  • Saki
  • Jesus is the Way and Salvation Evangelical Ministry - Jesus Itwasem

Jesus is the Way and Salvation Evangelical Ministry - Jesus Itwasem Welcome to this page. Do not forget the return of Jesus Christ the second time. Remember, there is J

17/12/2023

BI A TI N PARI ODUN YII LO, IRE WA TO KU NINU RE, YOO TE WA LOWO.

31/07/2023

BI O TI LE KOKO YII,MA BOKANJE,AYIPADA RERE YOO DE BA WA NI ORILE- EDE YII, IGBA OTUN RE YOO SOJU EMI WA,OSU YII YOO TU WA LARA O.

28/02/2023

OLUWA! ADUPE LOWO RE LONA GBOGBO,SUGBON BI O TI WU KI O RI I ,FUN WA NI IRORA NI ORILE EDE YII

01/02/2023

Ninu osu yii,Oluwa yoo la ona abayo nla fun yin,E o pitan ayo,Owo Olorun yoo wa lara yin fun rere.

17/12/2022
01/10/2022

OLORUN TO MU EMI YIN WA LAAYE, YIO YO YIN JADE KURO NINU IPONJU GBOGBO,YOO SI FUN YIN LORO RERE SO.

06/06/2021

Do not lose the hope of good things in your life, even if you are suffering in this life, your eternal life has been kept in Christ, this last storm will not overcome you.

Máse jé kí okàn re so ìrètí ohun rere nu nínú ayé re bi ìwo tilè n jìyà nínú ayé yìí, a ti fi ìyè re pamó nínú Krístì, ìjì ìkehìn yìí kò ni gbé o lo.

04/04/2021

: Nje nisisinyi Kristi ti jinde kuro ninu oku. Bi o ba se pe ni kiki aye yii nikan ni awa ba ni ireti ninu Kristi, awa jasi otosi julo ninu gbogbo eniyan. O le maa beere wi pe bawo ni Yoo ti se ji awon oku dide, iru ara wo ni won yoo pada si. Iwo alaimoye, ohun ti agbe ba funrugbin kii ye ,bi ko se pe o ba ku. Je ko ye o pe, laiku ninu eran ara , O le ye ninu Kristi ati pe, O si le ko pa ninu ajinde awon olooto. Da Jesu Kristi mo, Ki o to kuro ninu aye yii.

Now, Christ has risen from death. If our hope in Christ lies solemnly in this world, we are paupers. You might be wondering, how will He resurrect the dead, what sort of body would they be transformed into. You ignorant, what a farmer sow does not live, until it dies. Let it be know to you that, without being dead in flesh, you cannot live in Christ, also, you can not partake in the resurrection of the just. Know Jesus Christ, before you leave this world.

23/11/2020

I pray pertaining to the situation of this country, that God should intervene, it shouldn't take long for a change to come through, God shouldn't forsake us and forgive us our sins. This suffering is enough.

03/09/2020

God's love for you is so great than for you to loose your eternity, don't you forget home? be remembering home.
Matt.7:21-23.

Address

Olanrewaju Area
Saki

Telephone

+2348162238147

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Jesus is the Way and Salvation Evangelical Ministry - Jesus Itwasem posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Place Of Worship

Send a message to Jesus is the Way and Salvation Evangelical Ministry - Jesus Itwasem:

Share