Allahu Nuru

Allahu Nuru This is an Islam organization created to bring to you the messages of Allah

*ILE ÀIYÉ ASÁN*Ni ọjọ́ kàn, Ọmọkùnrin kan sọfún baba rẹ wípé, baba mi mo ri ọmọbìnrin kan tí o ní ẹwà púpọ, o si wu mi l...
02/10/2022

*ILE ÀIYÉ ASÁN*

Ni ọjọ́ kàn, Ọmọkùnrin kan sọfún baba rẹ wípé, baba mi mo ri ọmọbìnrin kan tí o ní ẹwà púpọ, o si wu mi lati fi se àyà, baba dáhùn oni:- *Kòsí wàhálà,* sùgbọ́n o, mofe ki o fi ọmọ naa hàn mí kí n le baọ baa sọrọ.

Baba ati ọmọ gba ọdọ ọmọbìnrin naa lọ, ni ìgbàtí wọn dé ọdọ arẹwà naa, *baba dáhùn ọ sọ wipe:-* irú iwọ kii se ẹni tí o yẹ lati fẹ arẹwà obìnrin yii o, sùgbọ́n irú emi gángan lo yẹ lati fẹẹ!

Bayii ni wàhálà sọ̀ kalẹ láàrín baba ati ọmọ, Ni awọn méjèjì ba ko ẹjọ lọ sí ọdọ adájọ.

*Adájọ ni ẹyìn méjèèjì ẹ n so ni ọdọ arẹwà obìnrin náà, bi adájọ se ri obìnrin yi ọ sọ wipe:-* ẹyìn méjèèjì ẹ ko yẹ l'ẹniti yíò fe arẹwà yi, sùgbọ́n àwọn adájọ bi t'émi yìí ni o ye ki wọn ọ fẹ arẹwà yi!

Bayii ni ija tun sẹlẹ láàrín baba ati ọmọ pẹlú adájọ, ni àwọn mẹtẹta ba tun ko ẹjọ lọ sí ọdọ *Ọtun Oba* nínú ìlú, *Ọtun Oba* dáhùn o ni ẹ n so l'ọdọ arẹwà náà, bayii ni *Ọtun ọba* náà tún sọ wípé: ẹyìn mẹtẹta ko yẹ lati dúró tí arẹwà yi óò, bi ko se wípé emi Ọtun Oba l'oyẹ lati fẹẹ, *bayii ni wàhálà tun sẹlẹ láàrín àwọn mẹrẹrin,* ni gbogbo wọn ba tún ko ẹjọ lọ sí ọdọ Oba ìlú, *kabi'esi dáhùn ọ sọ wipe:-* ẹ n so l'ọdọ arẹwà náà, *bayii ni Kabi'esi naa dáhùn wípé:-* arẹwà yii Olórí Oba ni o yẹ ki o jẹ óò, eyin mẹrẹrin e ko yẹ l'ẹniti yí ò fẹ arẹwà yi, *sùgbọ́n emi Kabiesi l'oyẹ lati fẹẹ,* bayii ni wàhálà nlá tún sọkalẹ sí àárín àwọn mararun oooo...

*Arẹwà náà wa dáhùn ọ sọ wipe:-* nkán ti à o se ree óò, èmi yíò s'áré ni iwájú yin, gbogbo yin e o ma l'émi bọ ẹnití ọwọ rẹ bá kọkọ kan mi ohun gangan ni yíò f'ẹmi ooo...

*Bayii kabi'esi* bọ Ade kalẹ ati Irùkẹ̀rẹ̀ ati ilẹkẹ ọrùn, *Ọtun Oba* náà bọ gbogbo nkán ara rẹ naa kalẹ

Bakanna ni Adájọ ati baba ati ọmọ wọn bọ gbogbo nkán arawọn kalẹ nítorí arẹwà obìnrin yii!

Arẹwà sáré gba ọnà ilé rẹ lo, ni ibití koto nlá kan wa, gbogbo wọn náà sáré tẹle, ni ibi ọgangan kòtò yi, bayii ni awọn mararun já sí inú kòtò óò ti wọn ko le jáde mọ, ni arẹwà wa dúró ní etí kòtò ọ sọwipe:- *njẹ ẹmọ mi?* Gbogbo wọn dáhùn won so wípé rara,

24/09/2022

Àwọn adura ti Anabi SAW ma nṣe

24/09/2022
15/09/2022

Hello here

Address

Oyo

Telephone

+2348135186846

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Allahu Nuru posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Place Of Worship

Send a message to Allahu Nuru:

Share