CCC Ipinnu Oluwa Cathedral

CCC Ipinnu  Oluwa Cathedral IPINNU OLUWA CATHEDRAL

19/04/2026

NJẸ igbagbọ́ ni idaniloju ohun ti a nreti, ijẹri ohun ti a kò ri. HEBERU 11:1

Now faith is the substance of things hoped for, the evidence of things not seen, HEBREWS 11:1










O si wi fun wọn pe, Ẹ lọ si gbogbo aiye, ki ẹ si ma wasu ihinrere fun gbogbo ẹda. MAKU 16:15And he said unto them, Go ye...
12/04/2026

O si wi fun wọn pe, Ẹ lọ si gbogbo aiye, ki ẹ si ma wasu ihinrere fun gbogbo ẹda. MAKU 16:15

And he said unto them, Go ye into all the world, and preach the gospel to every creature, MARK 16:15










He has Risen 🙏🌈🙏
05/04/2026

He has Risen 🙏🌈🙏










29/03/2026

Wipe, Olubukun li Ọba ti o mbọ̀ wá li orukọ Oluwa: alafia li ọrun, ati ogo loke ọrun, LUKU 19:38

Saying, Blessed be the King that cometh in the name of the Lord: peace in heaven, and glory in the highest, LUKE 19:38







15/03/2026










          Nigbati a lé ẹmi èṣu na jade, odi si fọhùn; ẹnu si yà awọn enia, nwọn wipe, A ko ri irú eyi ri ni Israeli. MAT...
22/02/2026












Nigbati a lé ẹmi èṣu na jade, odi si fọhùn; ẹnu si yà awọn enia, nwọn wipe, A ko ri irú eyi ri ni Israeli. MATIU 9:33

And when the devil was cast out, the dumb spake: and the multitudes marvelled, saying, It was never so seen in Israel. MATTHEW 9:33

          Nwọn si kó òkiti okuta nla kan lé e lori t**i di oni-oloni; OLUWA si yipada kuro ninu imuna ibinu rẹ̀. Nitorin...
15/02/2026












Nwọn si kó òkiti okuta nla kan lé e lori t**i di oni-oloni; OLUWA si yipada kuro ninu imuna ibinu rẹ̀. Nitorina li a ṣe npè orukọ ibẹ̀ li Afonifoji Akoru, t**i di oni-oloni. JOṢUA 7:26

And they raised over him a great heap of stones unto this day. So the LORD turned from the fierceness of his anger. Wherefore the name of that place was called, The valley of Achor, unto this day. JOSHUA 7:26

          Béè pẹlu, ẹnyin ipeerẹ, ẹ tẹriba fun awọn àgba. Ani, gbogbo yin, ẹ mã tẹriba fun ara nyin, ki ẹ si fi irẹlẹ wọ...
08/02/2026












Béè pẹlu, ẹnyin ipeerẹ, ẹ tẹriba fun awọn àgba. Ani, gbogbo yin, ẹ mã tẹriba fun ara nyin, ki ẹ si fi irẹlẹ wọ̀ ara yin li aṣọ: nitori Ọlọrun kọ oju ija si awọn agberaga, ṣugbọn O ń fi oore-ọfẹ fun awọn onirẹlẹ. PETERU KINNI 5:5

Likewise, ye younger, submit yourselves unto the elder. Yea, all of you be subject one to another, and be clothed with humility: for God resisteth the proud, and giveth grace to the humble. 1 PETER 5:5 🌈🙏🌈

          Nitorina, ẹ máṣe ṣe idajọ ohunkohun ṣaju akokò na, t**i Oluwa yio fi de, ẹniti yio mu ohun òkunkun ti o farasi...
25/01/2026












Nitorina, ẹ máṣe ṣe idajọ ohunkohun ṣaju akokò na, t**i Oluwa yio fi de, ẹniti yio mu ohun òkunkun ti o farasin wá si imọlẹ, ti yio si fi ìmọ ọkàn hàn: nigbana li olukuluku yio si ni iyìn tirẹ̀ lọdọ Ọlọrun. KỌRINTI KINNI 4:5

Therefore judge nothing before the time, until the Lord come, who both will bring to light the hidden things of darkness, and will make manifest the counsels of the hearts: and then shall every man have praise of God. 1 CORINTHIANS 4:5

HAPPY FIRST SUNDAY OF THE YEAR 2026 🌈🙏🌈
04/01/2026

HAPPY FIRST SUNDAY OF THE YEAR 2026 🌈🙏🌈










14/12/2025

Address

Phase 2, Elejigbo Estate, Behind Ogun State Housing Cooperation, Estate Bus Stop , Idiroko Road Ota
Otta
23401

Telephone

+2348037488547

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when CCC Ipinnu Oluwa Cathedral posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Place Of Worship

Send a message to CCC Ipinnu Oluwa Cathedral:

Share