Ajigbare prayer group

Ajigbare prayer group Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Ajigbare prayer group, Religious organisation, prayer mountain @ the back of CAC NO 9 oke onitea osogbo, Osogbo.

09/01/2023

GBOGBO OGUN ADOOMO.GBOGBO OGUN OJU KAN.GBOGBO OGUN IPONJU.GBOGBO OGUN IRAHUN.GBOGBO OGUN OSI ATI AINI.GBOGBO OGUN INIRA GBOGBO OGUN E MA SEE LAANU.E MAA RANAN LOWO.LONI OLUWA FI INA RUN WON DANU.OLUWA JEKI ARA TU MI NINU ODUN YI.EJEKI EMI NAA RI AANU GBA BEENI KI E FI ORO MI JO OTA LOJU OTI RI BEE ERI SI MAA TE LEE NI ORUKO JESU.

09/01/2023

ibukún wọnyi yio si ṣẹ sori rẹ, yio si bá ọ, bi iwọ ba fetisi ohùn OLUWA Ọlọrun rẹ.

3 Ibukún ni fun ọ ni ilu, ibukún ni fun ọ li oko.

4 Ibukún ni fun ọmọ inu rẹ, ati eso ilẹ rẹ, ati irú ohunọ̀sin rẹ, ati ibisi malu rẹ, ati ọmọ agutan rẹ.

5 Ibukún ni fun agbọ̀n rẹ ati fun ọpọ́n-ipò-àkara rẹ.

6 Ibukún ni fun ọ nigbati iwọ ba wọle, ibukún ni fun ọ nigbati iwọ ba jade.

09/01/2023

*Psalms 84:11*
Beloved, I pray for you that every second, minute, hour, day, week and month of this new year shall favor and prosper you. People will serve your God. Your life will be decorated and beautified with good things always. Your light will shine so brightly. The glory of the Lord God Almighty will be obvious in your life, home, work, endeavours and undertakings. As you go in His might and surely as the Lord lives, God will beautify your life and will do a new thing in your life. You shall not fall away from the grace of God and your life will be a living proof of God's glory, grace, favour and mercy in this new year and beyond. I prophesy and declare, Heavens will perpetually open for you, such that you will not lack any good thing and you will not be put to shame. Beloved, whosoever rises against you shall fall for your sake, and no evil shall come near your dwelling in the mighty name of Jesus Christ..

Address

Prayer Mountain @ The Back Of CAC NO 9 Oke Onitea Osogbo
Osogbo
233082

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ajigbare prayer group posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share