08/07/2021
Today's hymn
Various hymn 6
V006
1. Iwo to le wa la o ma sin t**i
Oluwa Olore wa;
Iwo to nso wa n'nu idanwo aye,
Mimo, logo Ola Re,
Baba, Iwo l'a o ma sin,
Baba, Iwo lâa o ma bo,
Iwo to fe wa l'a o ma sin t**i,
Mimo lâogo Ola Re
2. Iwo to nsure sâohun tâa gbin sâaye
Tâaye fi nrohun je o;
Awon to mura lati ma sâoto,
Won tun nyo nânu ise Re
3. Iwo to nfâagan lâomo to npe ranse
Ninu ola Re to ga;
Eni tâo ti sâalaileso si dupe
Fun âse ogo ola Re.
4. Eni tâebi npa le ri ayo ninu
Agbara nla Re to ga,
Awon to ti nwoju Re fun anu
Won tun nyo nânu ise Re
5. Fâalafia Re fun ijo Re lâaye
Kâore-ofe Re ma ga.
Kâawon eni Tire ko ma yo t**i
Ninu ogo ise Re
Amin.