Abundant Life Baptist Church, Ogunrun, Mowe.

Abundant Life Baptist Church, Ogunrun, Mowe. The official page of Abundant Life Baptist church, Ogunrun Eletu, Mowe, Ogun State.

26/08/2026

*BIBA OLORUN PADE LOJOOJUMO (NBC YORUBA)*

*WEDNESDAY, AUGUST 26, 2026*

*OBINRIN OLOKOWO TO KAJUẸ*

*YBH 314: Igbagbọ Mi N WọỌ*
IGBAGBO mi nwo O
1. IGBAGBO mi nwo O,
Iwo Od’-agutan,
Olugbala
Jo gbo adua mi,
M’ ese mi gbogbo lo,
K’ emi lat’ oni lo
Si je Tire.

2. Ki ore-ofe Re
F’ ilera f’ okan mi,
Mu mi tara:
B’ Iwo ti ku fun mi,
A! k’ ife mi si O,
K’ o ma gbona t**i,
Ina iye

3. ‘Gba mo rin l’ okunkun,
T’ ibinu yi mi ka,
S’ amona mi,
M’ okunkun lo loni,
N’ omije anu nu,
Lai, ma je ki nsako
Li odo Re.

4. Gbati aiye ba pin,
T’ odo tutu iku,
Nsan lori mi;
Jesu, ninu ife,
Mu k’ ifoiya mi lo,
Gbe mi d’ oke orun
B’ okan t’ a ra.

*Ese Lati Ranti:* O kiyesi i pe ọja oun dara; fitila rẹ ko ku ni oru. Owe 31:18.

*Bibeli Kika: Owe 31:10-22*

[10] Tani yio ri obinrin oniwà rere? nitoriti iye rẹ̀ kọja iyùn.

[11] Aiya ọkọ rẹ̀ gbẹkẹle e laibẹ̀ru, bẹ̃ni on kì yio ṣe alaini ère iṣẹ.

[12] Rere li obinrin na yio ma ṣe fun u, kì iṣe buburu li ọjọ aiye rẹ̀ gbogbo.

[13] Obinrin na yio ma ṣafẹri kubusu ati ọ̀gbọ, o si fi ọwọ rẹ̀ ṣiṣẹ tinutinu.

[14] O dabi ọkọ̀ oniṣowo: o si mu onjẹ rẹ̀ lati ọ̀na jijin rére wá.

[15] On a si dide nigbati ilẹ kò ti imọ́, a si fi onjẹ fun enia ile rẹ̀, ati iṣẹ õjọ fun awọn ọmọbinrin rẹ̀.

[16] O kiyesi oko, o si mu u: ère ọwọ rẹ̀ li o fi gbin ọgbà-ajara.

[17] O fi agbara gbá ẹ̀gbẹ rẹ̀ li ọjá, o si mu apa rẹ̀ mejeji le.

[18] O kiyesi i pe ọjà on dara: fitila rẹ̀ kò kú li oru.

[19] O fi ọwọ rẹ̀ le kẹkẹ́-owú, ọwọ rẹ̀ si di ìranwu mu.

[20] O nà ọwọ rẹ̀ si talaka; nitõtọ, ọwọ rẹ̀ si kàn alaini.

[21] On kò si bẹ̀ru òjo-didì fun awọn ara ile rẹ̀; nitoripe gbogbo awọn ara ile rẹ̀ li a wọ̀ li aṣọ iṣẹpo meji.

[22] On si wun aṣọ titẹ́ fun ara rẹ̀; ẹ̀wu daradara ati elese aluko li aṣọ rẹ̀.

_______

Ọnkọwe kan ti o gbajugbaja sọ nigba kan pe, "Awon obinrin takuntakun ti won ṣe aṣeyọri n fihan pe ẹru ikuna wa lẹjẹ ọta wa ti o di ẹkọ ti o ṣe pataki julọ ninu aye wa (ẹkọ ti o le ran wa lọwọ lati ni aṣeyọri ti o ga lọjọ iwaju!)."

Iwe owe sọrọ pupọ nipa awọn obinrin. Ọna ti o dara ti iwe naa fi pari ni aworan obinrin oniwabajẹ, ọgbọn ti o lagbara, oniruru ọgbọn atinudá ati aamú ti o jinlẹ.

Abala ẹkọ ti oni n gba awa ọdọ ati awọn obinrin aṣeṣẹ gbeyawo nimọran lati jẹ akinkanju, ki wọn si gẹgẹ bi iya Lemueli Ọba ti gbẹ kọ kale.

O ṣe apejuwe rẹ gẹgẹ bi obinrin takuntakun ati onịṣowo ti o ni ọgbọn atinudá lati ṣedaa, lati ṣe eto, ati lati ṣe akoso okowo, o ma n fori la ewu lati mu erongba rẹ ṣe nigba ti o n ṣe akoso ile rẹ.

O maa n misi, o si maa n gbun awọn ara ile rẹ ni kẹsẹ inu, o maa n tan iṣẹ kara-kara fun igba pipẹ ni ọṣan ati ni oru ki o le ni aṣeyọri.

Obinrin ti a ṣe apejuwe ninu abala ẹkọ ti oni jẹ iwuri fun gbogbo onigbagbọ; a le kẹkọọ lara imura iṣẹ, iṣọtitọ, ati ọna ti o n gba pese fun idile rẹ.

Gẹgẹ bii onigbagbọ, ifẹ Ọlọrun ni pe ki o jere, yoo si dara fun ọ ninu gbogbo awọn idawọle rẹ, paapaa julọ fun imugbooro ijoba Rẹ.

Gẹgẹ bii onigbagbọ aṣeyọri, o gbọdọ ko ipa ti o dara lati maa nipa lori aye awọn eniyan ti o wa ni ayika rẹ.

Nje o si n gba Ọlọrun gbọ lati di nla? Kẹpẹ E fun itọni, ati iranlowọ. Olotiitọ ni lati ro ọ lagbara lati mu erongba rẹ ṣe.

*Ọrọ Ọgbọn:* Jẹ ki aṣeyọri rẹ ni gbogbo agbọn aye rẹ ṣe deede pẹlu bi o ṣe n ṣe daadaa ninu ile ati ninu ijọ rẹ.

*Ọrọ fun Ironu:* Bi o ba jẹ wi pe iwọ nikan ni o n jẹ anfaani aṣeyọri rẹ, o ko tii ṣe aṣeyọri niti ijoba naa.

*Iṣẹ Ṣịṣẹ:* Bi o ṣe n gbadura fun idanwo/ikọduro lati bẹrẹ idokowo lati bẹrẹ katakara kanni oṣu yii.

*Adura:* Oluwa, fun mi ni ikọra-ẹni-ni-ijanu ati ọgbọn atinudá lati wa ojutuu si awọn iṣoro, ni orukọ Jesu.

*Adura:* Oluwa, yọ wa ninu gbogbo ibi.

*Gbadura fun awọn Ẹni-Ọwọ wọnyi, idile ati awọn ọmọ Ijo Ọlọrun:* Ayuba Danlami, Dada; Samson Adejumo, Ogbomọṣọ; Kolawole A. Akinlade, Ibadan; Ojoogun O. Timothy, Ibadan; Abayomi A. Ogunkunle, Ibadan; James S. Sati, Mapejuku; Samuel O. Olabisi, Ilorin.

*KBJL: Ẹsikiẹli 9:12*

26/08/2026

*DAILY ENCOUNTER WITH GOD (NBC)*

*WEDNESDAY, AUGUST 26, 2026*

*A CAPABLE AND ENTREPRENEURIAL WOMAN*

*BH 257: My Faith Looks Up to Thee*

1. My faith looks up to Thee,
Thou Lamb of Calvary,
Savior divine!
Now hear me while I pray,
Take all my guilt away,
O let me from this day
Be wholly Thine.

2. May Thy rich grace impart
Strength to my fainting heart,
My zeal inspire;
As Thou hast died for me,
O may my love to thee
Pure, warm and changeless be,
A living fire.

3. While life's dark maze I tread,
And griefs around me spread,
BeThou my guide;
Bid darkness turn to day,
Wipe sorrow's tears away,
Nor let me ever stray
From Thee aside.

4. When ends life's transient dream,
When death's cold, sullen stream
Shall o'er me roll,
Blest Savior, then, in love,
Fear and distrust remove;
O bear me safe above,
A ransomed soul! Amen

*Golden Text:* She sees that her trading is profitable, and her lamp does not go out at night. Proverbs 31:18, NIV

*Text: Proverbs 31:10-22*

[10] A wife of noble character who can find? She is worth far more than rubies.

[11] Her husband has full confidence in her and lacks nothing of value.

[12] She brings him good, not harm, all the days of her life.

[13] She selects wool and flax and works with eager hands.

[14] She is like the merchant ships, bringing her food from afar.

[15] She gets up while it is still night; she provides food for her family and portions for her female servants.

[16] She considers a field and buys it; out of her earnings she plants a vineyard.

[17] She sets about her work vigorously; her arms are strong for her tasks.

[18] She sees that her trading is profitable, and her lamp does not go out at night.

[19] In her hand she holds the distaff and grasps the spindle with her fingers.

[20] She opens her arms to the poor and extends her hands to the needy.

[21] When it snows, she has no fear for her household; for all of them are clothed in scarlet.

[22] She makes coverings for her bed; she is clothed in fine linen and purple.

_______

A renowned writer once said, “These strong accomplished women demonstrate that our fear of failure can be our greatest enemy and that any venture gone awry can actually turn into our most important life lesson (a lesson that helps us find even greater success later!).”

The book of Proverbs speaks extensively about women. How appropriate that the book ends with a picture of a woman of strong character, great wisdom, diverse skills and deep compassion.

Today's passage encourages young and newly married women to be industrious and well behaved in their homes. Solomon gives accounts in the book of Proverbs, a model woman through the words of King Lemuel's mother.

He described her as a woman of great capacity and entrepreneurial skill to create, organise, and manage a business venture, taking risks to achieve her goals while managing her home.

She inspires and motivates her family members, solves their problems, and was very devoted to her goals, working long and hard day and night to achieve them.

The woman described in today's passage serves as an inspiration to all believers; we can learn from her industry, integrity, and resourcefulness.

As a believer, God's desire is that you will be profitable and prosperous in your endeavours, especially for the advancement of His Kingdom

As a successful believer, you should positively impact the lives of people around you.

Are you still trusting God for greatness? Call on Him for guidance, and help. He is faithful to empower you to fulfil your purpose.

*Wisdom:* Let your success in all areas of life be matched by how well you are doing at home and in your local assembly.

*Food for Thought:* If you are the only beneficiary of your success, you are not yet successful in the Kingdom.

*Follow-up Action:* As you pray for God's leading, explore your entrepreneurial ability to start a trade this month.

*Prayer:* O Lord, give me the discipline and skills to solve problems, in Jesus name.

*Prayer:* Lord, deliver us from all evil.

*Pray for these ordained ministers and members of their churches:* AyubaDanlami, Dada; Samson Adejumo, Ogbomoso; Kolawole A. Akinlade, Ibadan; Ojoogun O. Timothy, Ibadan; Abayomi A. Ogunkunle, Ibadan; James S. Sati, Majeuku; Samuel O. Olabisi, Ilorin.

*RBT: Ezekiel 9-12*

26/08/2026

*SEEK DAILY (NBC)*

*Wednesday, August 26, 2026*

*A CAPABLE, ENTREPRENEURIAL WOMAN*

*Golden Text:* “A wife of noble character who can find? She is worth far more than rubies.”
— Proverbs 31:10, NIV

*Text: Proverbs 31:10–22*

[10] A wife of noble character who can find? She is worth far more than rubies.

[11] Her husband has full confidence in her and lacks nothing of value.

[12] She brings him good, not harm, all the days of her life.

[13] She selects wool and flax and works with eager hands.

[14] She is like the merchant ships, bringing her food from afar.

[15] She gets up while it is still night; she provides food for her family and portions for her female servants.

[16] She considers a field and buys it; out of her earnings she plants a vineyard.

[17] She sets about her work vigorously; her arms are strong for her tasks.

[18] She sees that her trading is profitable, and her lamp does not go out at night.

[19] In her hand she holds the distaff and grasps the spindle with her fingers.

[20] She opens her arms to the poor and extends her hands to the needy.

[21] When it snows, she has no fear for her household; for all of them are clothed in scarlet.

[22] She makes coverings for her bed; she is clothed in fine linen and purple.

_______

Belinda Gates is an American businesswoman and philanthropist who co-founded the Bill and Melinda Gates Foundation.

The Bill and Melinda Foundation works to solve health problems of people around the world.

Her capability and commitment as an entrepreneurial woman have not only helped her immediate family but also contributed to assuaging society's health problems.

The passage presented a portrait of a noble and capable entrepreneurial woman, emphasising her preciousness in her skilful and productive lifestyle, and her devotion to the wellbeing of her household.

She is an asset contributing spiritually, emotionally and financially to her family.

Her home becomes a centre of ministry, reaching out to the poor, training her children and domestic workers in true and kind service.

Her husband and children receive joy and are honoured because of her noble character in her society, as she is a good example to other women.

In today's morally corrupt world, we need capable, productive and godly women who can influence their family and society positively and in the way of the Lord.

A true woman of virtue is not a liability but an asset in God's hands.

What kind of person are you becoming for your family and society?

*Insight:* A noble and entrepreneurial woman is useful and valuable in the hands of God.

*Prayer:* God, I pray for grace to be an asset and not a liability to my family and the society in Jesus' name.

*RBT Passage: Ezekiel 9–12*

24/08/2026

*SEEK DAILY (NBC)*

*Monday, August 24, 2026*

*STEWARDS OF GOD’S GOOD GIFTS*

*Golden Text:* "Each of you should use whatever gift you have received to serve others, as faithful stewards of God's grace in its various forms."
— 1 Peter 4:10 NIV.

*Text: 1 Peter 4: 7-11*

[7] The end of all things is near. Therefore be alert and of sober mind so that you may pray.

[8] Above all, love each other deeply, because love covers over a multitude of sins.

[9] Offer hospitality to one another without grumbling.

[10] Each of you should use whatever gift you have received to serve others, as faithful stewards of God’s grace in its various forms.

[11] If anyone speaks, they should do so as one who speaks the very words of God. If anyone serves, they should do so with the strength God provides, so that in all things God may be praised through Jesus Christ. To him be the glory and the power for ever and ever. Amen.

______

I read a story about a lady named Sarah. She was a gifted musician who sang to the glory of God.

Many people who come to worship in the church receive edification and healing.

As an exceptional musician in the church, she became proud and abandoned singing to God’s glory, but decided to use her gifts solely for personal recognition and financial gain, forgetting the God who entrusted it to her. Instead of remaining a faithful steward, she misused her gift.

Apostle Peter encouraged his audience to live for God and people wholeheartedly as a matter of necessity.

The passage depicts that every believer is gifted with one gift or another, and each gift is given to serve and glorify God.

Believers are to use these gifts, including spiritual and material gifts, diligently and faithfully to minister to one another at all seasons.

What gift has God given you for the service of the people and the church? How are you using the gift?

Is it for self-recognition or God’s glory? We must discharge the gift of the word we have received and share the material gifts given to us by God as good stewards. May God use us for His glory.

*Insight:* Stewardship is good when God’s gifts are used according to the master’s will and direction.

*Prayer:* Lord, give me the grace to be a faithful steward of Your good gifts in Jesus’ name.

*RBT Passage: Ezekiel 1-4*

24/08/2026

*BIBA OLORUN PADE LOJOOJUMO (NBC YORUBA)*

*ỌṢẸ KARUN-LẸ-LỌ́GBỌ̀N: August 30, 2026*

*LIDIA, ẸNI TI A DA LARE LATI JẸ OLỌTITỌ*

*Iṣẹ Awọn Aposteli 16:11-15, 40*

*ẸṢẸ LATI RANTI:* Nigba ti a si baptisi rẹ, ati awọn ara ile rẹ, o bẹ wa wi pe, bi ẹyin ba ka mi si olooto si Oluwa, ẹ wa si ile mi, ki ẹ si wo nibẹ. O si rọ wa. — Iṣẹ Awọn Aposteli 16:15

*MONDAY, AUGUST 24, 2026*

*IRIJU AWỌN ẸBUN ỌLỌRUN TI O DARA*

*YBH 337: Mo ti Ṣeleri Jesu*

1. MO ti se ‘leri, Jesu,
Lati sin O d’ opin;
Ma wa lodo mi t**i,
Baba mi, Ore mi,
Emi k’ y’o beru ogun,
B’ Iwo ba sunmo mi,
Emi ki y’o si sina,
B’ O ba f’ ona han mi.

2. Je kin mo p’ O sunmo mi,
‘Tor’ ibaje aiye;
Aiye fe gba okan mi,
Aiye fe tan mi je,
Ota yi mi kakiri,
L’ ode ati ninu;
Sugbon Jesu sunmo mi,
Dabobo okan mi.

3. Je ki emi k’ o ma gbo,
Ohun Re, Jesu mi,
Ninu igbi aiye yi,
T**i nigbagbogbo,
So k’ o f’ okan mi bale,
Te ‘ri okan mi ba;
So k’ emi le gbo Tire,
‘Wo Olutoju mi.

4. ‘Wo ti se ‘leri Jesu
F’ awon t’ o tele O,
Pe ibikibi t’ O wa,
L’ awon yio si wa;
Mo ti se ‘leri Jesu,
Lati sin O d’ opin,
Je kin ma to O lehin,
Baba mi, O re mi.

5. Je kin ma ri ‘pase Re
Ki nle ma tele O:
Agbara Re nikan ni,
Ti mba le tele O,
To mi, pe mi, si fa mi,
Di mi mu de opin
Si gba mi si odo Re,
Baba mi, Ore mi.

*Ese Lati Ranti:* Bi olukuluku ti ri ẹbun gba, bẹẹni ki ẹ maa ṣe ipinfunni rẹ ni aarin ara yin, bi iriju rere ti oniruru oore-ọfẹ Ọlọrun. — Peteru Kinni 4:10

*Bibeli Kika: Peteru Kinni 4:7-11*

[7] Ṣugbọn opin ohun gbogbo kù si dẹ̀dẹ: nitorina ki ẹnyin ki o wà li airekọja, ki ẹ si mã ṣọra ninu adura.

[8] Jù gbogbo rẹ̀ lọ, ẹ ni ifẹ ti o gbóna larin ara nyin: nitori ifẹ ni mbò ọ̀pọlọpọ ẹ̀ṣẹ mọlẹ. [9] Ẹ mã ṣe ara nyin li alejò laisi ikùn sinu.

[10] Bi olukuluku ti ri ẹ̀bun gbà, bẹ̃ni ki ẹ mã ṣe ipinfunni rẹ̀ larin ara nyin, bi iriju rere ti onirũru ore-ọfẹ Ọlọrun.

[11] Bi ẹnikẹni ba nsọ̀rọ, ki o mã sọ bi ọ̀rọ Ọlọrun; bi ẹnikẹni ba nṣe iṣẹ iranṣẹ, ki o ṣe e bi agbara ti Ọlọrun fifun u: ki a le mã yìn Ọlọrun logo li ohun gbogbo nipa Jesu Kristi, ẹniti ogo ati ìjọba wà fun lai ati lailai. Amin.

_______

Johanu dagba lati fẹ Oluwa. Ki i ṣe ipejọpọ jẹ o si n ṣe isin ninu oriṣiriṣii awọn ẹka iṣẹ-iranṣẹ ninu iijọ, ni ile abinibi rẹ.

O ni ẹbun ohun ti o rẹwa lati kọrin, laipẹ o di ọkan lara awọn awọn aladari orin.

Johanu lọ ẹbun ti Ọlọrun fun un lati iṣe isin lotitọ ati lati kọ awọn miiran ninu igbagbọ, ko kan lo ẹbun rẹ ki wọn le ri i, ṣugbọn fun iṣẹ-iranṣẹ.

Aposteli Peteru gba awọn onigbagbọ niyanju lati gbe igbe-aye pẹlẹpẹlẹ pẹlu ọgbọn ki wọn si duro ṣinṣin ninu adura bi wọn ṣe n duro de opin ohun gbogbo.

O rọ wọn ki wọn fẹran ara wọn wọn denu-denu ki wọn si mi ṣiṣẹ pẹlu awọn onigbagbọ miiran pẹlu awọn ẹbun ẹmi wọn.

Oniruru ni awọn ẹbun Ẹmi; lara wọn ni iṣọtẹlẹ, iṣe-isin, ikọni, idari, aanu, ọrọ ọgbọn, ọrọ imọ, iṣẹ iyanu, iwosan, ida ẹmi mọ, ifedefọ, ati itumọ ede (Koriinti Kinni 12:8-10).

Ọlọrun fi awọn ẹbun wonyi fun gbogbo awa onigbagbọ lati ṣiṣe sin ara wa pẹlu ati ifarajin.

Peteru tun tẹsiwaju lati ran wọn leti pe, gẹgẹ bi ẹni ti o ni awọn ẹbun naa, wọn gbọdọ lo awọn ẹbun wọn lati fi ogo fun Ọlọrun.

Nje o ti ṣawari awọn ẹbun ẹmi rẹ? Nje o n lo awọn ẹbun ẹmi rẹ lati ṣiṣe sin awọn onigbagbọ yooku ninu ara Kristi?

Awọn ẹbun rẹ ko wa fun ogo ara rẹ, ko wa fun okiki, tabi ere ara ẹni, ṣugbọn fun ibukun ijọba Ọlọrun ati lati ro ijọ lagbara.

Ṣiṣe sin pẹlu ifẹ, irẹlẹ, ati otitọ inu, nipa lilo awọn ẹbun rẹ lati gbẹro ati lati mu awọn onigbagbọ yooku dagba, gẹgẹ bi o ṣe jẹ ifẹ-ọkan Ọlọrun.

*Ọrọ Ọgbọn:* Ifẹ rẹ fun Ọlọrun ati awọn miiran yoo ṣe agbẹkalẹ agbegbe ti o dara lati lo awọn ẹbun rẹ.

*Ọrọ fun Ironu:* Nje o n kọ ijọba Ọlọrun pẹlu ẹbun ẹmi rẹ tabi o n ṣe agbega ara rẹ?

*Iṣẹ Ṣiṣe:* Lo awọn ẹbun ẹmi rẹ lati ṣiṣẹ sin awọn onigbagbọ mẹta ni ọṣẹ yii.

*Adura:* Oluwa, ṣi mi ni oju ki n le ri awọn ẹbun ẹmi ti O ti fun mi, ni orukọ Jesu.

*Adura:* Oluwa, mu awọn ti o n ṣaarẹ pada si ilera pipe lẹkunrẹrẹ, ni orukọ Jesu.

*Gbadura fun awọn Ẹni-Ọwọ wonyi, idile ati awọn ọmọ Ijọ Ọlọrun:*
Owolabi O. Ojo, Eko; Arikewe S. Olugbenga, Eko; Kasiwa Y. George, Kaduna; Matthew Ayanlude, Abidjan; Esada O. Godsent, Elume; Simeon A. Ademola, Oṣogbo; Abraham K. Babarinde, Iwo; Austine O. Imonitanre, Warri; J.A. Elewode, Ogboroṣọ; I.A. Diẹkola, Ogbomọṣọ; Oludele Gabriel, Ogbomọṣọ; Oyerinde A. Michael, Ogbomọṣọ; Olurogba S. Adebisi, Ibadan; David T. Olaoye, Ibadan; Olaleye Gideon, Kaba; Abayomi A. Ogunkunle, Ibadan.

*KBJL: Esikieli 1:1-4*

24/08/2026

*DAILY ENCOUNTER WITH GOD (NBC)*

*WEEK 35: August 30, 2026*

*LYDIA, JUDGED TO BE FAITHFUL.*

*Text: Acts 16:11-15, 40.*

*GOLDEN TEXT:* When she and the members of her household were baptised, she invited us to her home. 'If you consider me a believer in the Lord,' she said, 'come and stay at my house.' And she persuaded us. Acts 16:15.

*MONDAY, AUGUST 24, 2026*

*STEWARDS OF GOD'S GOOD GIFTS*

*BH 354: Thou My Everlasting Portion*

1. Thou, my everlasting portion,
More than friend or life to me;
All along my pilgrim journey,
Savior, let me walk with Thee.
Close to thee. Close to thee
Close to thee, close to thee;
All along my pilgrim journey.
Savior, let me walk with Thee.

2. Not for ease or wordly pleasure,
Not for fame my prayer shall be;
Gladly will I toil and suffer,
Only let me walk with Thee’
Close to Thee, close to thee
Close to Thee, close thee;
Gladly will I toil and suffer
Only let me walk with Thee

3. Lead me thro’ the vale of shadows,
Bears me o’er life’s fitful sea;
Then the gate of life eternal
May I enter Lord, with Thee,
Close to Thee,close to Thee
Close to Thee, close to Thee;
Then the gate of life eternal
May I enter, Lord with Thee.

*Golden Text:* "Each of you should use whatever gift you have received to serve others, as faithful stewards of God's grace in its various forms." 1 Peter 4:10, NIV

*Text: 1 Peter 4:7-11*

[7] The end of all things is near. Therefore be alert and of sober mind so that you may pray.

[8] Above all, love each other deeply, because love covers over a multitude of sins.

[9] Offer hospitality to one another without grumbling.

[10] Each of you should use whatever gift you have received to serve others, as faithful stewards of God’s grace in its various forms.

[11] If anyone speaks, they should do so as one who speaks the very words of God. If anyone serves, they should do so with the strength God provides, so that in all things God may be praised through Jesus Christ. To him be the glory and the power for ever and ever. Amen.

______

John grew to love the Lord. He never missed a fellowship and served in various ministries at his home church. Gifted with a beautiful singing voice, he soon became one of the church's lead singers.

John used this God-given gift to serve faithfully and to train others in the faith, using his talent not just for performance, but for ministry.

Apostle Peter encouraged believers to live soberly and remain steadfast in prayer as they await the end of all things.

He urged them to love one another deeply and serve other believers with their spiritual gifts.

Spiritual gifts are diverse; they include prophecy, serving, teaching, leadership, mercy, words of wisdom, words of knowledge, miracles, healing, distinguishing between spirits, speaking in tongues, and interpretation of tongues (1 Corinthians 12:8-10).

God gives these gifts to all believers to serve one another with love and commitment.

Peter further reminded them that as custodians of the gifts, they must use their gifts to glorify God.

Have you identified your spiritual gifts? Have you been using your spiritual gifts to serve other believers in the body of Christ?

Your gifts are not meant for self-glory, fame, or personal gain, but for blessing God's Kingdom and strengthening the church.

Serve with love, humility, and sincerity, using your gifts to edify and build up fellow believers, just as God intended.

*Wisdom:* Your love for God and others creates a good environment to express your gifts.

*Food for Thought:* Do you build God's Kingdom with your spiritual gifts or promote yourself?

*Follow-up Action:* Use your spiritual gifts to serve three believers this week.

*Prayer:* Lord, open my eyes to see the spiritual gifts You have given me, in Jesus' Name.

*Prayer:* Lord, restore to full health those who are sick, in Jesus' name.

*Pray for these ordained ministers and members of their churches:*
Owolabi O. Ojo, Lagos; Arikawe S. Olugbenga, Lagos; Kasiwa Y. George, Kaduna; Matthew Ayanlude, Abidjan; Esada O. Godsent, Elume; Simeon A. Ademola, Osogbo; Abraham K. Babarinde, Iwo; Austine O. Imonitanure, Warri; J.A. Elewode, Ogbomoso; I.A. Diekola, Ogbomoso; Oludele Gabriel, Ogbomoso; Oyerinde A. Michael, Ogbomoso; Olurogba S. Adebisi, Ibadan; David T. Olaoye, Ibadan; Olaleye Gideon, Kaba; Abayomi A. Ogunkunle, Ibadan.

*RBT: Ezekiel 1-4*

22/08/2026

*SEEK DAILY (NBC)*

*Sunday, August 23, 2026*

*CONTINUE IN WHAT YOU HAVE LEARNED*

*Golden Text:*"But as for you, continue in what you have learned and have become convinced of, because you know those from whom you learned it."
— 2 Timothy 3:14, NIV

*Text: 2 Timothy 3:10-11, 14-16*

[10] You, however, know all about my teaching, my way of life, my purpose, faith, patience, love, endurance,

[11] persecutions, sufferings—what kinds of things happened to me in Antioch, Iconium and Lystra, the persecutions I endured. Yet the Lord rescued me from all of them.

[14] But as for you, continue in what you have learned and have become convinced of, because you know those from whom you learned it,

[15] and how from infancy you have known the Holy Scriptures, which are able to make you wise for salvation through faith in Christ Jesus.

[16] All Scripture is God-breathed and is useful for teaching, rebuking, correcting and training in righteousness,

______

A devout disciple named Jack Nike was deeply influenced by his spiritual leader, Father John, a wise and compassionate Monk.

After the demise of Father John, Jack continued to spread his teachings, establish a community, and inspire others through his own life, service and contemplation with commitment and without shame.

In this passage, Paul wrote to his son, Timothy, to warn him against false teachers who twisted the truth of the gospel and their teachings, which were scattered everywhere as impostors corrupting the gospel.

He encouraged Timothy to continue his sound teaching, godly life, faith, patience, and conduct just as he had learned from him and his godly family from childhood.

Paul told Timothy to avoid corrupt teachers and remain faithful to the sacred writing he has learned from, which is profitable for all things.

Today, many are led astray by popular voices rather than godly examples.

As believers, we must be careful about who we learn from and also ensure that the teaching we listen to align with God's word.

We must also hold on to the truth of Christ and live it out, so that others can also learn from it and be transformed.

*Insight:* You are only a disciple of Jesus if you continue to teach and live like Him.

*Prayer:* God, help me to continue teaching the message of the Bible I have received in Jesus' name.

*RBT Passage: Lamentations 3-5*

22/08/2026

*DAILY ENCOUNTER WITH GOD (NBC)*

*SUNDAY, AUGUST 23, 2026*

*CONTINUE IN WHAT YOU HAVE LEARNED*

*BH 347: Wherever He Leads I'll Go*

1. “Take up thy cross and follow Me,”
I heard my master say;
“ I gave My life to ransom thee,
Surrender your all today,”
Wherever He leads I’ll go,…
Wherever He leads I’ll go,…
I’ll follow my Christ who loves me so,
Wherever he leads I’ll go.

2. He drew me closer to His side,
I sought His will to know,
And in that will I now abide,
Wherever He leads I’ll go,

3. It may be through the shadows dim,
Or o’er the stormy sea,
I take my cross and follow Him,
Wherever He leadeth me.

4. My heart, my life, my all I bring
To Christ who loves me so;
He is my Master, Lord, and king,
Wherever He leads I’ll go.

*Golden Text:* But as for you, continue in what you have learned and have become convinced of, because you know those from whom you learned it.
— 2 Timothy 3:14, NIV

*Text: 2 Timothy 3:10-11; 14-16*

[10] You, however, know all about my teaching, my way of life, my purpose, faith, patience, love, endurance,

[11] persecutions, sufferings—what kinds of things happened to me in Antioch, Iconium and Lystra, the persecutions I endured. Yet the Lord rescued me from all of them.

[14] But as for you, continue in what you have learned and have become convinced of, because you know those from whom you learned it,

[15] and how from infancy you have known the Holy Scriptures, which are able to make you wise for salvation through faith in Christ Jesus.

[16] All Scripture is God-breathed and is useful for teaching, rebuking, correcting and training in righteousness,

______

Abigail Adams said, “Learning is not attained by chance. It must be sought for with ardour and attended with diligence.”

Learning is not a matter of chance or casual exposure; it requires deliberate, passionate pursuit, intention, discipline, and sustained effort.
This passage continues Paul’s admonition to Timothy, his son in the Lord.

Paul charged Timothy to remain strong in the faith, reminding him of virtues to uphold and attitudes to avoid in the face of persecutions and sufferings associated with a believer’s life.

This charge implies that Timothy must hold firmly to his knowledge of God's Word, as it is the only way to overcome the increase of deception and lies of the enemy.

Timothy was one of the first second-generation Christians, not because an evangelist preached to him, but because his grandmother and mother had taught him the Word of God from infancy.

Therefore, as he grew to make life’s decisions, he was to remember the training he had received and live according to the Word of God.

In a society filled with fake spiritual leaders, you must be firmly grounded in the Word of God.

These individuals often speak very sweet and persuasive words as though they speak the truth.

However, like Paul charged Timothy, you should also continue in the faith you have received and become convinced of by immersing yourself in the diligent study of God’s Word. It is the only path that will make you wise for the right decision.

*Wisdom:* The Christian journey can often be tough and challenging, but it is admirable and desirable to all.

*Food for Thought:* Do you still weigh your decisions by the Word of God?

*Follow-up Action:* Always subject your decisions to the Word of God.

*Prayer:* Lord, fill me with Your strength to continue with what I have received. Help me to keep cherishing what I have in Jesus’ Name. Amen!

*Prayer:* Lord, comfort and strengthen each person who is suffering for righteousness’ sake.

*Pray for these ordained ministers and members of their churches:* Segun Owolabi, Lagos; Otun M.O., Ekiti; Olorunfemi Emmanuel I., Ekiti; Solomon I. Michael, Aso-pada; Sunday O. Owadoyin, Apomu; Grace Owumi, Delta; Doris T. Esiedape, Ughelli; Josiah A. Owolabi, Ogbomoso; Taiwo Agunloye, Ogbomoso; Ezra Dangson, Filiyal; Israel I. Olabiyi, Awe.

*RBT: Lamentations 3-5*

22/08/2026

*BIBA OLORUN PADE LOJOOJUMO (NBC YORUBA)*

*SUNDAY, AUGUST 23, 2026*

*TẸSIWAJU NINU OHUN TI O TI KỌ*

*YBH 317: Jesu Agbara Mi*

1. JESU, agbara mi,
Iwo l’ aniyan mi,
Emi fi igbagbo w’ oke,
Iwo l’ O ngb’adua.
Jeki nduro de O,
Ki nle se ife Re,
Ki Iwo Olodumare
K’o so mi di otun.

2. Fun mi l’ okan ‘rele,
Ti ‘ma se ara re;
Ti ntemole, ti ko nani
Ikekun Satani:
Okan t’ ara re mo
Irora at’ ise;
T’ o nfi suru at’ igboya
Ru agbelebu re.

3. Fun mi l’ eru orun,
Oju t’ o mu hanhan,
T’y’o wo O n’gb’ ese sunmole,
K’ o ri b’ Esu ti nsa.
Fun mi ni emi ni,
T’ O ti pese tele.
Emi t’ o duro gangan lai
T’ o nf’ adura s’ ona.

4. Mo gbekel’ oro Re
‘Wo l’ o leri fun mi;
Iranwo at’ igbala mi
Y’o t’ odo Re wa se,
Sa je kin le duro,
K’ ireti mi ma ye,
Tit’ Iwo o fi m’ okan mi
Wo ‘nu isimi Re.

*Ese Lati Ranti:* Ṣùgbọ́n ìwọ duro ninu nkan wọnyí ti ìwọ ti kọ́, ti a sì ti jẹ́ kii ojú rẹ daju si, ki ìwọ ki o sì mọ ọ̀dọ̀ ẹnì ti ìwọ gbè kọ́ wọn.
— Timotiu Keji 3:14.

*Bíbélì Kíkà: Timotiu Keji 3:10-11; 14-16*

[10] Ṣugbọn iwọ ti mọ̀ ẹkọ́ mi, igbesi aiye mi, ipinnu, igbagbọ́, ipamọra, ifẹ́ni, sũru,

[11] Inunibini, iyà; awọn ohun ti o dé bá mi ni Antioku, ni Ikonioni ati ni Listra; awọn inunibini ti mo faradà: Oluwa si gbà mi kuro ninu gbogbo wọn.

[14] Ṣugbọn iwọ duro ninu nkan wọnni ti iwọ ti kọ́, ti a si ti jẹ ki oju rẹ dá ṣáṣa si, ki iwọ ki o si mọ̀ ọdọ ẹniti iwọ gbé kọ́ wọn;

[15] Ati pe lati igba ọmọde ni iwọ ti mọ̀ iwe-mimọ́, ti o le sọ ọ di ọlọ́gbọn si igbala nipasẹ igbagbọ́ ninu Kristi Jesu.

[16] Gbogbo iwe-mimọ́ ni o ni imísi Ọlọrun ti o si ni ère fun ẹkọ́, fun ibaniwi, fun itọ́ni, fun ikọ́ni ti o wà ninu ododo:

______

Abigail Adams wi pe, “Ẹ̀kọ́ kíkọ́ kiì ṣe èsì. A gbọdọ̀ wa pẹ̀lú gbogbo agbára ki a sì mojú tó gidi gidi.”

Ẹ̀kọ́ kíkọ́ kiì ṣe ọ̀rọ̀ ṣíṣe kopá, bẹ́ẹ̀ ni kiì ṣe gbẹ̀fẹ́; àmọ́ ọn mọ gba, ilẹ̀pa pẹ̀lú ọkàn, pẹ̀lú ìkorá-ẹni-níjánu àti ìpásẹ́ ti o n tẹsiwaju.
Abala ẹ̀kọ́ yii n tẹsiwaju lori ìyanjú Pọọlu sí Timotiu, ọmọ rẹ̀ ninu Olúwa.

Pọọlu rọ Timotiu lati jẹ́ alagbara ninu ìgbàgbọ́, o ran an letí àwọn àmuyẹ ti o ni lati dimú, bẹ́ẹ̀ ni kò ṣaí mẹnuba àwọn ìyà ti o rí lati yago fun ni àkókò inúnibíni àti ìjìyà ti o rọ mọ́ ìgbé-ayé onígbàgbọ́.

Ìpènìjà yii tumọ si pe Timotiu gbọdọ̀ mọ̀ pe ajyìinrere kan waṣu fun un, ṣùgbọ́n nitori pe ìyá-ńlá àti ìyá rẹ̀ kò ní Ọlọ́run lati ìgbà ewe.

Nitori naa, bi o ṣe n dagba lati ṣe ìpinnu lori ìgbé-ayé, o ní lati manti ẹ̀kọ́ ti o ti gba, ki o sì gbe ni ìbámu pẹ̀lú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.

Ninu awujọ ti o kun fun awọn ayederu oludari ti emi, o gbọdọ̀ fí ẹ̀kan mulẹ̀ daadaa ninu Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.

Àwọn ẹnìyan wọnyí maa n sọ̀rọ̀ dundun ati awọn ọ̀rọ̀ ti inu Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ti o ti gba ki o sì maa kekoo ninu Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run deede. Ó jẹ́ ọna kan ṣoṣo ti o le mu ọ gbọ́n lati ṣe ìpinnu ti o tọ́.

*Ọ̀rọ̀ Ọgbọ́n:* Ìrin-ajò Kristiani le lagbara, ko si mu ìpènìjà lọ́wọ́, ṣùgbọ́n o maa n dùn, o si maa n wu ọ̀pọ̀lọpọ̀.

*Ọ̀rọ̀ fun Ìrònú:* Nṣe o si maa n gbe ìpinnu rẹ lẹ́wọ̀n pẹ̀lú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run?

*Ìṣe Ṣíṣe:* Maa ṣe ìpinnu rẹ gẹ́gẹ́ bíi idarí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run nigba gbogbo.

*Àdúrà:* Olúwa, kun mi pẹ̀lú okùn Rẹ lati tẹsiwaju pẹ̀lú ohun ti mo ti gba. Ran mi lọ́wọ́ ki n le maa mọyì ohun ti mo ní, ní Orúkọ Jesu. Amin!

*Adura:* Oluwa, tu gbogbo awọn ti o n jiya nitori ododo ninu ki O si fun wọn ni okun.

*Gbadura fun awon Ẹni-Ọ̀wọ̀ wọnyí, ìdílè àti awọn Ọmọ Ìjọ Ọlọ́run:*
Ṣẹgun Owolabi, Eko; Otun M.O., Ekiti; Ọlọ́runfẹ́mi Emmanuel I., Ekiti; Solomon I. Michael, Aso-pada; Sunday O. Owadoyin, Apomu; Grace Owumi, Delta; Doris T. Esiedape, Ughelli; Josiah A. Owolabi, Ogbomoso; Taiwo Agunloye, Ogbomoso; Ezra Dangson, Filiyal; Israel I. Olabiyi, Awẹ.

*KBJL: Ẹkun Jeremiah 3-5*

Address

Ogunrun Eletu, Phase III, Church Street, MOWE
Ogun

Telephone

+2348058034659

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Abundant Life Baptist Church, Ogunrun, Mowe. posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Place Of Worship

Send a message to Abundant Life Baptist Church, Ogunrun, Mowe.:

Shortcuts

Share

Category