01/06/2026
Awa Omo ijo Peter Beatrice OGUNNIYI memorial Gospel Baptist church Papa Abede Ogbomoso Oyo State. Nkiyin sir ma fun Osu titun yii ooooo, ti o bawa.laye ati laaye. Gbogbo Awa Omo ijo yii lapapo wa gbe ohun Adura soke funnyin wipe e.Alafia ni yio je ipin tiwa ninu Osu titun yii ooooo.A o si koju sewa loore. Aifayabale ati ipayin keeke yio si dopin. Okan gbogbo wa patapata yio si bale ooooo.Oluwa yio si ma pa Aalo ati Aabo wa mo oooo. Happy new month. Ni Oruko Jesu Kristi Oluwa wa oooooooooo.