Ẹkọ Bibeli NI Yoruba

Ẹkọ Bibeli NI Yoruba Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Ẹkọ Bibeli NI Yoruba, Religious organisation, Lagos.

IDANI LEKO OFE OLOJO MEJE NBO LONA
02/02/2026

IDANI LEKO OFE OLOJO MEJE NBO LONA

28/01/2026

Kí ni ìtumọ̀ “ìmísí Ọlọ́run” gẹ́gẹ́ bí 2 Tímótì 3:16?
👉 Kí ló mú kí Bíbélì yàtọ̀ sí gbogbo ìwé míì tí ènìyàn kọ?
Ese bible 2 Timotiu 3:16; 2 Peteru 1:21

15/01/2026

Ìbéèrè Ìjíròrò 3
Kí ló dé tí a fi sọ pé gbogbo Bíbélì ń tọ́ka sí Jésù Kristi?
👉 Ṣe o lè sọ àpẹẹrẹ kan láti Májẹ̀mú Àtijọ́ tàbí Májẹ̀mú Tuntun?

15/01/2026

Ìbéèrè Ìjíròrò 2
Gẹ́gẹ́ bí Róòmù 15:4, kí ni àǹfààní Ìwé Mímọ́ nínú ìgbésí-ayé onígbàgbọ́?
Báwo ni Bíbélì ṣe ń fún wa ní ìkọ́ni, ìfaradà àti ìrètí?

15/01/2026

Ìbéèrè Ìjíròrò 1
Kí ni ìtúmọ̀ Bíbélì sí ọ?
Ṣé o rí i gẹ́gẹ́ bí ìwé ìtàn nìkan, tàbí gẹ́gẹ́ bí Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tí ń sọ̀rọ̀ sí ìgbésí-ayé wa lónìí?

TANI LE BAWA SALAYE, GBOLO-UN ORO BIBELI YIOKU NIGBATI O WA LAYETIMOTI KINNI 5:6[6]Ṣugbọn ẹniti o ba fi ara rẹ̀ fun aiye...
10/01/2026

TANI LE BAWA SALAYE, GBOLO-UN ORO BIBELI YI
OKU NIGBATI O WA LAYE
TIMOTI KINNI 5:6
[6]Ṣugbọn ẹniti o ba fi ara rẹ̀ fun aiye jijẹ, o kú nigbati o wà lãye.
EBAWA FERAN RE, KI ESI BAWA PIN KAAKIRI, E SEUN

AISAYA 45:2Emi o lọ siwaju rẹ, emi o si sọ ibi wiwọ́ wọnni di titọ́: emi o fọ ilẹkùn idẹ wọnni tũtũ, emi o si ke ọjá-iri...
08/01/2026

AISAYA 45:2
Emi o lọ siwaju rẹ, emi o si sọ ibi wiwọ́ wọnni di titọ́: emi o fọ ilẹkùn idẹ wọnni tũtũ, emi o si ke ọjá-irin si meji.

AISAYA 45:1[1]BAYI ni Oluwa wi fun ẹni-ororo rẹ̀, fun Kirusi, ẹniti mo di ọwọ́ ọtún rẹ̀ mu, lati ṣẹ́gun awọn orilẹ-ède n...
08/01/2026

AISAYA 45:1
[1]BAYI ni Oluwa wi fun ẹni-ororo rẹ̀, fun Kirusi, ẹniti mo di ọwọ́ ọtún rẹ̀ mu, lati ṣẹ́gun awọn orilẹ-ède niwaju rẹ̀; emi o si tú amure ẹgbẹ awọn ọba, lati ṣi ilẹkùn mejeji niwaju rẹ̀, a ki yio si tì ẹnu-bode na;

Address

Lagos

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ẹkọ Bibeli NI Yoruba posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share