Ogo oluwa musical and evangelical band

Ogo oluwa musical and evangelical band To build up talented people physically and spiritually

U r all invited
21/12/2016

U r all invited

Ogo oluwa musical and evangelical band
03/12/2016

Ogo oluwa musical and evangelical band

New face of ogo oluwa musical and evangelical band. Fun Gbogbo eyin te ri awon egbe ogo oluwa te si se amin, ogo oluwa k...
03/12/2016

New face of ogo oluwa musical and evangelical band. Fun Gbogbo eyin te ri awon egbe ogo oluwa te si se amin, ogo oluwa ko fara han ninu aye bi o ti wo inu odun titun lo.

Bi odun 2016 yii se n pari lo, mo so pelu ase ati agbara ipe, wipe o ni pari odun 2016 yii lowo ofo
29/11/2016

Bi odun 2016 yii se n pari lo, mo so pelu ase ati agbara ipe, wipe o ni pari odun 2016 yii lowo ofo

16/11/2016

Bi o ti n lo lowuro yi oju oluwa ko ma ba e lo
Anu olorun ko wa aye re ri
Owo agbara olodumare ko gbe aye re dide
O ni kan agbako aburu, enieleni o ni gba ise re se
Ipadabo re loni ko mu ayo wa fun
O ri bee, ko yii pada ase orun gun jesu oluwa wa

Olorun yio fa emi ati iwo lowo soke nine ose laaarin opo eniyan
14/11/2016

Olorun yio fa emi ati iwo lowo soke nine ose laaarin opo eniyan

13/11/2016

The Lord work for six days and rested on the seventh day
In all ramifications of life, you shall experience rest........ Happy Sunday to ogo oluwa love once

11/11/2016

Gbo bi oluwa awon omo ogun ti wi
Alejo ti ki i kan ilekun ile
Ko to wole eni
To je wipe ko ni ore to mu wa
Afi ko gba omije kikoro loju eni
Bi odun 2016 yii se n lo si opin
Iru alejo bee ko ni mona ile re

10/11/2016

Fun iwo okan to ri amin nla meta se, mo so ni bi oluwa ti n be ti emi re n be pelu Gbogbo panpe iku lori e, ebi e ati irin ajo aye re, ki aanu oluwa pa won sona patapata

Address

6 Omola Road Odomola Epe
Lagos

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ogo oluwa musical and evangelical band posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share