The c/s unification churches, holy Mary band

The c/s unification churches, holy Mary band Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from The c/s unification churches, holy Mary band, Religious organisation, Imole aiyeraye ona iyanu c/s, Lagos.

30/11/2019

NI ORUKO JESU BI ODUN YI TIPARILO,O NI BODUN LO,ONISOFO,LORI EBI RE,LORI ILE RE,NI ORI OHUN ANUMONI RE,WA RI OWO FI SE ODUN YI LAYO,INU EMI ATI RE YIO DUN NI ORUKO JESU OLUWA WA, GOOD morning IYA ADURA J.O A OYENIYI

24/11/2019

NI ONI TI NSE SUNDAY TI O GBEYIN NINU OSU KOKANLA,FUN I WO TI ORI AMIN ATI CONFIRM SE,NI ORUKO JESU, AYO RE AKU AKUWOSILE,,ONI MO INIRA,ONIMO IKORO WA FEHINTI JEUN OMO,ONI JEUN OMO LORI WIN CHAIR, ONI SUKUN LORI OMO,AGBEJULE RE KONI JASOFO,ONI RI IDIBAJE LORUKO JESU OLUGBALA WA AMIN,EKU OJUMO IYA ADURA J.O.A.AFOLABI

MOGBA LADURA FUN IWO ATI EMI,NI ORUKO JESU,TI ABARI OJO TI SATANI YA SILE GEGEBI OJO  YEYEE EMI ATI IWO, OWO TOYI OWO PA...
23/11/2019

MOGBA LADURA FUN IWO ATI EMI,NI ORUKO JESU,TI ABARI OJO TI SATANI YA SILE GEGEBI OJO YEYEE EMI ATI IWO, OWO TOYI OWO PADA SAWARI OJO NA,OYI PADA SI OJO AYEYE,LATI ONI LO OLORUN YIN GBA AYE WA PADA SI RERE, BI JESU BALE SEGUN AYE MO PA LASE LATO NI LO ,OGUN JIJA AYE EMI ATI IRE DOPIN,NI OJO OLOGO AO NI DENI AWATI JESU OLUWA WA AMIN,EKU OJUMO,IYA ADURA J.O.A AFOLABI,A.K.A .HOLY MARY

21/11/2019

OLORUN TO GBO TI ELIJAH ,LEBA ODO JORDANI OLORUN TO GBO TI ESTHER TO SI SEGUN HAMMANI,NI OWURO MOGBA LADURA FUN IWO TO NI GBAGBO TO SILE. SAMI META YI NI ORUKO JESU OLORUN YIO GBO ADURA,OHUN RERE KONI JE EWO FUN EE,IWO TO WOJU OLUWA FUN IBISI ,OLORUN YIO FUN O NI OMO RERE,INU WA YIO DUN,A O ROHUN RERE GBAMU,AYO ATI ALAFIA TI AFI BERE ODUN YI LAMA FI PARI E,LORUKO JESU OLUWA WA AMIN,EKU OJUMO O,IYA ADURA J.O.A. AFOLABI

20/11/2019

Olorun to yi igbe aye jabesi pada, ti o so do lorire,mo wi pelu ase ipe loni,bi Iwo ba gbagbo o ri ogo olorun,ni oruko Jesu Krist gbogbo igbe aye ese togbe yen olorun fa o yo kun ro nibe, yio yi aye re pada si rere,ilekun anu yio si fun ninu ose yi ni orun Jeovah,ni oni tise ojo anu ,olorun yio fanu wa aye wa ri,so rire gbamu lopin odun yi ,a o ni je ikoro ni orun Jesu Oluwa wa amin,eku ojumo iya adura J .O .A .Afolabi

17/11/2019

IRE OWO,OMO,AYO,ALAFIA,EMI GIGUN ATI AIKU LEWE YIO FILE WA SE IBUGBE MOGBA LADURA,FUN GBOGBO OKAN TO GBAGBO LORUKO JESU, IYANU AYO YIO SELE NINU AYE EMI ATI IRE,A O NI ERI RERE,NINU OSE YIN OKAN WA ABALE NI ORUKO JESU OLUGBALA WA,AMIN,EKU ISINMI ONI O IYA ADURA J.O AFOLABI

16/11/2019

Mo gbaladura fun emi ati eyin,NI oruko Jesu igbese ise rere ti Iran wa,logbe ri,orun mu wagbe,anu tokoja IMO enia,yio sawari loni,majemu ise rere ojo totipe, yio wa si imuse,aWA ni Erin kan

13/11/2019

Moduro Lori apata Jesu krist,mofehin ti agbelebu,mo tenure bo eje Jesu Krist mo wo ni oruko Jesu,emi ati a o inu ise rere wa,loni,anu to koja IMO enia,yio sawari wa,inu wa yo sun kale,a o ni sinku omo,ati wo inu ise rere,eka San iya adura afolabi oyeniyi

12/11/2019

Gbo,gbogbo eyin abiyemo aye,ni oruko Jesu,won oni fiku omo se wa to,aye o ni fi wa sesi, a o ni sunkun Lori omo,loruko Jesu o ni mo iboji omo,gbogbo wa la o jeun omo,Adun wa koni di ibaje,ao ni sa set I oun rere, a o ni si ara wa lo si tee,,a o ni fekun pari odu

Address

Imole Aiyeraye Ona Iyanu C/s
Lagos

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when The c/s unification churches, holy Mary band posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share