Hounsou Victor prayer page

Hounsou Victor prayer page All about the word of God....Watch and pray, that ye enter not into temptation: the spirit indeed is

Bẹrẹ sí ní dupẹ lọwọ Ọlọrun gẹgẹ bí ẹni to more fun anu àti ore-ọfẹ to fi mú ọ wọnú osun yi ni ayọ àti alafia...Sọ fún p...
31/10/2022

Bẹrẹ sí ní dupẹ lọwọ Ọlọrun gẹgẹ bí ẹni to more fun anu àti ore-ọfẹ to fi mú ọ wọnú osun yi ni ayọ àti alafia...
Sọ fún pe : JESU o seun..

Mọ gbàdúrà fún ẹnìkán to se amin..Ogun to bá ọ parí òsun yi ko ni bá ọ wọnú osun to mbọ....
31/10/2022

Mọ gbàdúrà fún ẹnìkán to se amin..Ogun to bá ọ parí òsun yi ko ni bá ọ wọnú osun to mbọ....

Ọmọ inú ọkà ló n'se ku p'oka, ọmọ inú ọgẹdẹ ló n'se ku p'ọgẹdẹ...Gbogbo ero ibí ọtá lori rè ati lori awọn ọmọ rẹ̀ ninu ọ...
30/10/2022

Ọmọ inú ọkà ló n'se ku p'oka, ọmọ inú ọgẹdẹ ló n'se ku p'ọgẹdẹ...Gbogbo ero ibí ọtá lori rè ati lori awọn ọmọ rẹ̀ ninu ọsẹ yí kò ṣe kù p'awọn...Amin..

28/10/2022

People will celebrate you in the name of JESUS CHRIST..

26/10/2022

Gbogbo emi olubewo ti a fi ise ran loru Oni nitori aye emi ati yin Olorun majemu ko so won sinu ide...

Ile Oni mon ki ama gbohun eye tabi ti eniyan..Gbo ni ibi to ye ko ti soro ki itan aye re ba le yipada si rere fun eni to...
26/10/2022

Ile Oni mon ki ama gbohun eye tabi ti eniyan..Gbo ni ibi to ye ko ti soro ki itan aye re ba le yipada si rere fun eni to ri Amin se ni Oruko Olorun awon omo ogun lo soro nibe...

Opo ni won ni iran(vision) to dara sugbon ko si agbara imuse Iran.....Awon alagara ile awon mi ti gbe ese le Iran ti won...
24/10/2022

Opo ni won ni iran(vision) to dara sugbon ko si agbara imuse Iran.....
Awon alagara ile awon mi ti gbe ese le Iran ti won...
Sugbon mo wi ni Oruko Baba Omo Emi mimo , fun eni to ba le pariwo Amin.. gbogbo ese ajeji Lori Iran ori re, Loni afa ijoba re ya....

Fun eni to ri Amin se...Ni Oruko Baba Omo ati ti Emi mimo, ina ogo aye re tan pada...
19/10/2022

Fun eni to ri Amin se...Ni Oruko Baba Omo ati ti Emi mimo, ina ogo aye re tan pada...

05/06/2021
Majemu agbara kaka Lori aye re, mo pase, majemu oruko Jesu ko gbemi....
30/01/2021

Majemu agbara kaka Lori aye re, mo pase, majemu oruko Jesu ko gbemi....

24/01/2021

Majemu anu ma fohun fun wa ninu ose yi ni Oruko JESU....
Amin...

Address

Lagos

Telephone

+2348103359483

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Hounsou Victor prayer page posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share