CAC Mount of Salvation Lafiagi

CAC Mount of Salvation Lafiagi CAC OKE IGBALA Lafiagi is located at Emir's Road P.O Box 28, Lafiagi

10/10/2025

Jesus did not only die for you, He died as you.

*** OHUN IJINLE TO YE KO MO NIPA PALM SUNDAY ***Mo Fe Jeki O Ri EKO Nla Yi, Ti O Farasin Ninu Awon Isele Ti O Sele Ni Oj...
13/04/2025

*** OHUN IJINLE TO YE KO MO NIPA PALM SUNDAY ***

Mo Fe Jeki O Ri EKO Nla Yi, Ti O Farasin Ninu Awon Isele Ti O Sele Ni Ojo Palm Sunday Ninu Bibeli. E Wo Ese Yi.

9 Ijọ enia ti nlọ niwaju, ati eyi ti ntọ̀ wọn lẹhin, nkigbe wipe, Hosanna fun Ọmọ Dafidi: Olubukun li ẹniti o mbọ̀ wá li orukọ Oluwa; Hosanna loke ọrun.



(Mathew 21 vs 9 NKJV)

Awon Ijo Eniyan Ti Nlo Niwaju Jesu Ati Eyi Ti nto Lehin Ni Ojo Na, Ti Won Pariwo Hosanna Fun Omo Mary , Hosana Fun Omo Dafidi Awon Ijo Eniyan Yi Kana Ni Won Pariwo Ni Ose Keji Wipe , E Kan Mo Agbelegbu. E Ma Gbagbe Pe, Gbogbo Odun Meta Ati Abo Ti Jesu Lo Laye, Awon Eniyan Yi, Lo Fi Sin. Beeni O Rorun Fun Won, Lati So Pe, Ki Won Kan Jesu Pa, Nigbati kii se Awon Lo Bi. Awon Eyan Yi, Je Ninu Ounje Kristi, Won Je Eja E, Won Je Isu_Akara Re, Ani Ni Aje Yo (Johannu 6:27) Sibe Sibe Won Ko, Won Si Ropo Re Pelu Barabba Eniti O Han Won Ni Heemo Ti N Pa Won Lara (Luku 22:19).Ni Ojo Yen, Bi Won Se Lu Jesu Teje Bo Gbogbo Ara Re, Ti Won Si Fa Losi Golgotha, Jesu Yi Oju Re Si Awon Eyan Ti Won Se Ikanu Ati Idaro Re (Luku 23:27) Jesu Si So Fun Won Wipe, " Nitori bi nwon ba nse nkan wonyi sara igi tutu, kini ao se sara gbigbe ?" Luku 23:31. Nje Awon Eniti O Fi Ori Se, Fi Orun Nse Fun, Wa Da Nigbati Nkan Sapere ?.Nje Se Kin Se Awon Ore Re Ti O Gbekele, Ti Won Je ninu Ata Ati Epo Re, Koni Won Lo Ba E Je Leyin Bi ? Psalm 41:9. Awon Ero Ti Won Pejo Si Ile E, Ti Won Yin E Loju E, Nitori Iranlowo Ti Won Ri Gba Lowo E,Nigbati Oda De, Se Won Wa Elomiran Lo ?. Bi Won Ba Nse Nkan Wonyi Si Olorun Ti O Sokale lati Orun Wasi Aiye Ni Iriri Eniyan, Kini Won Wa Ni Se Si Eyin Eniyan Ti Abi Ninu Aiye (Filippi 2:7-8).

Gbo Mi, Ti O Ba Ti Ba De Ibi Wipe, Awon Eniyan Ti N So Wipe, Afi Iwo, Afi Iwo, Tete Ma So Fun Pada Wipe, Afi Olorun, Bo Ba Je Wakati Kan Ni O Fi Gba Adura Ni Akoko Na, Tete Yi Si Wakati Meji. Nitoriwipe, Awon Eniyan Ti On So Wipe Afi Iwo Afi Iwo Yi, Ti Ri Ore-Ofe Olorun

03/10/2022
03/10/2022

LETTER TO A CHRISTIAN CORPER

Day 33 of 61 Days || 3rd of October, 2022

Share this letter with everyone you know across all social media platforms!

Watch out for the Christian Corpers’ Summit 1.0 || 11th November, 2022

Venue: NCCF Oyo State secretariat, Oniyanrin, off airport road, Alakia Ibadan.
Supported by: NCCF, OYO State Chapter.

Subscribe to Victor Olukoju PVO YouTube Channel for faith-based movies.
Here is the link:
https://youtube.com/c/VictorOlukojuPVO

I am PVO (Victor Olukoju)


#

CAC Senior Choir Lafiagi
03/09/2022

CAC Senior Choir Lafiagi

Address

P. O Box 28 Emir Road
Lafiagi

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when CAC Mount of Salvation Lafiagi posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share