30/01/2025
Kini iwu'ri Olorun ni’nu igbala wa? Kini oun to sun Olorun lati se igbala fun iran eniyan to da’le Re, to si s’ote si?
Ninu eko yi, a se agbeyewo oun to sun Olorun lati gba iran eniyan elese la, gege bi Bibeli ti se afihan re. Se awari bi ife àti iwa rere Olorun, anu, ore-ofe, àti suru Re se ise lati my igbala wa fun iran eniyan.
📖 Awon koko inu eko yi:
✔️ Igbala gege bi abajade eni ti Olorun fun’ra Re je.
✔️ Ipa ti ife àti iwa rere, anu, ore-ofe, àti suru Olorun ko ninu igbala wa.
🔔 Da’rapo mo ikanni yi fun awon eko Bibeli to jin’le miran: [https://www.youtube.com/]
👍 Feran, f’esi, ki o si fi ikoni yi ran’se si awon elomiran lati je ibukun fun won!
📢 Te le wa l'ori awon ikanni ibanid’ore wonyi:
✅ Facebook: [https://www.facebook.com/share/1U7sSTLgen/?mibextid=qi2Omg]
✅ YouTube: [https://www.youtube.com/]
✅ Website: [http://www.hccchurchonline.org/]