Imam Gentle Lectures

Imam Gentle Lectures If you need husband or wife we are here to connect you with ure choice

04/12/2025
04/12/2025
04/12/2025
04/12/2025
04/12/2025
04/12/2025
13/08/2025

ASIRI TI OMO ARAIYE FI NFI IRE WA EYAN RI....

*Ori/Shea butter
*Iyo/Salt
*Ose dudu/Ose ghana/Black soap

gbe olo /grinding stone ti a fi nlo ata si ita ninu oorun (under the sun)
A o bu iyo si oju olo,a o te ka (spread)
A o fi ori si oju olo naa pelu
A o fi sile ti yoo fi yo (melt)tan patapata.
A o wa fi ose ko loju olo naa.

∆..A o ma fi we laraaro.....
O daju.

01/08/2025

FUN IWO TOMA JEUN LOJU ORUN, IBALOPO LOJU ORUN, FIFI OJU KO JAKARIWO KAKIRI ,IFAYALUAYA PELU OBINRIN TABI OKUNRIN , KIO MA RI AWON ENIYAN TOTIKU LOJU ALA, .KI OLORUN ALAGBARA KO SEGUN YIN LONIi.

OPOLOP OMO OLOGO LOJIYA AIMODI LONI, TI OPOLOPO TIFI OGO OMO WON TAFALA NIBI.. ORO ENU, ONJE JIJE A*O ALA*O WIWO,, OWO BIBA ( HAND CHECK) ATI BEBE LOOO

OPOLOPO ENIYAN 🗣️, LOFI OGO RE PAMO TOSI JE ONJE IPONJU OMI IPONJU TORI PE OGO RE TINBE NINU TUBU ( PRISON👮😷👮🚓👮😷👮🚓👮😷👮)

OPOLOPO OMO OLOGO LONI NI AWON IKA ENIYAN ATI ODAJU ALAGBARA OKUNKUN TI FI OUNJE IPONJU ATI ISE IBI SINU AGO ARA RE LATI OJU ALA..ELOMI IBALOPO LOJU ORUN,...TI AWON ISE IBI TO FARA HAN LOJU AIYE,...
TI ONIRURU IKAN SELE SI WON..BI OGUN AISAN , AMUBO, IJAKULE, GBESE, IFASEHIN,ANI AKOJO,..
NITORI OUNJE OJU ORUN TI AWON ALAGBARA OKUNKUN FUN WON JE....🗣️MO GBALADURA FUN O KIO LOMAGBA ITUSILE LATI ONILO ..
OLORUN ALAYE GBOGBO OUNJE IPONJU ATI OMI INILARA NINU AGO ARA RE ,INA OLORUN ELEDUNMARE KO TI GBOGBO RE JADE LONI AMIN🙏🙏🙏🙏....FUN ETO ADURA ATI ONA-ABAYO LORI ALAKALA, IBALOPO LOJU ORUN, OUNJE OJU ORUN, FIFI OJU KO JAKARIWO, OGUN AMUBO, OGUN EJE MI NI,..
Kasi Alfa Adura Yanjue call or whatsapp 07015993868

29/07/2025

★ ★ By Alfa Adura Yanjue

Bi ose bami share post yi fun anfani opo eniyan waari ogo aye re lo amin.

Odara kii amò ilu tabi agbegbe ti odara fún ipin ati iseda irawo wa nitori kii amaba wa laye bíi aláìsí bẹ sini kii amaba di ẹni ẹyin.

Mofeki amo daju wipe kii se gbogbo nkan náà níí ota fii ùn dáwà láàmú besini kii ùn se gbogbo nkan níí ogun ìdílé

Ejeki amo ilu ti odara fún ipin irawo wa gẹgẹ bíi àpẹẹrẹ;

*IBUGBE IRAWO INA*

Ejeki abere Lori irawo ina pupo ninu awon iseda yii Agaga awontii wonbii nii Ojo Monday oro won kii duro lojukan pupo ninu won je Akiikanju wonsi ma ungba ero nkan nlala.

*ILU TI WỌN LÈ GBÉ*

Odara kii wọn magbe ilu tabi agbegbe ti Oke posi (mountain) wọn tún legbe ilu tabi Adugbo tii Afefe waa daada kii wongbiyanju lati jekii igi wanii Ile tiwonba Kọ fún arawọn nitoripe Afefe aleje oluran lowo fun wọn

*PẸLU ÀFIKÚN*

Iseda won nkan giga giga nii wọn má ungba lero ju

Iseda yii saba má ùn ló nkan pupa sugbon wonkii un mọ elomiran ninu won ma un mu Oti kii unse ebii won bikii se iseda irawo won.

*IBUGBE IRAWO AFEFE*

Oba irawo nii irawo yii je kosi ibiti kole gbe won feran latii maase ibere daada won si je eyankan tii oma ùn beru pupo ninu won kii un sábà ma un gbagbo pe eyankan wanii idi Oro awon nitoripe isada won nii Agbara gan wonje oloju Aanu
Bii wonba unparo Ifaseyin die die ama waye funwon

*ÌLÚ TÍ WONLEGBE*

Iseda yii koferan OOru, beeni Wonko feran idoti
Kosi ilu tii Afefe kolegbe sugbon odara kii irawo yii maa gbe ilu tabi Adugbo tii Omi posi. Daada.

*IBUGBE IRAWO OMI*

Kosi Eda Alaye tii oleba irawo yii see ota ti koni pada kabamo lopin igbati onirawo yi bati mojuto oro ara e nitori pataki wonpo lawujo

*ÌLÚ TIWONLEGBE*

Odara fun irawo yii komaagbe Adugbo tii Omi tabi Alafia ma nwa daada nitoripe Omi kii unse ota eyankankan bii Oni irawo Omi ba ungbe ilu tabi Adugbo tii Omi tabi Alafia ba ùn wa odidandan kii irawo ati Ogo ee matesiwaju

Diẹ ninu awọn onirawo yii elegbe niwon egbe bii.
Omo Omi.

Emere Omi

Iranse Aje

Alaragbo

Ati Bebe lo.

*IBUGBE IRAWO ERUPE*

Odarakii irawo yii magbe ibiti Ero baapo daada nitoripe kosi eniti olemo iwa iru irawo yii tan
Irawo yìí féràn ilu tabi agbegbe ti kii ba ùn da nítorí pé kii ògo ati arisiki ee lè tètè tẹ lọwọ

Die Lara awon Obinrin irawo yii Je elegbe bii

Iranse Àjé

Igi Aje

Omi Anu

Omi àjé

*ÌLÚ TI WONLEGBE*

Ilu tabi Adugbo tii awon eyan ba Saba maun posi nii odaraju fun irawo won nitori pe àjé kii ùn fẹ ki gbogbo agbegbe tí òun bawa ma dull
Pataki julo àwọn tí wọn ùn ló ipin iseda irawo erupe funfun.

waari ogo e lo lagbara eleduwa amin.
Fun ibere call or whatsapp 07015993868

29/07/2025
29/07/2025

Address

28 Anifowoshe Street
Ilorin

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Imam Gentle Lectures posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share