Oro itunu

Oro itunu the word of God

07/02/2023

Am back to my page now
ORO ITUNU
Try and follow my page ooo
God bless u all

Gbo gbogbo eda eniyan Gbogbo eni to ba ni ohun ma gba a*o ogo Lara ki iru enibe ko wo inu ide ayeraye lo 👏👏👏
27/06/2021

Gbo gbogbo eda eniyan
Gbogbo eni to ba ni ohun ma gba a*o ogo Lara ki iru enibe ko wo inu ide ayeraye lo 👏👏👏

Mark my Words..👈 Before 25th May of this year, Unexpected Financial Favor will hit the person that will type AM£N & $har...
19/05/2021

Mark my Words..👈
Before 25th May of this year, Unexpected Financial Favor will hit the person that will type AM£N & $hare.

23/04/2021

ORIN DAFIDI 15:1-5
[1]OLUWA, tani yio ma ṣe atipo ninu agọ rẹ? tani yio ma gbe inu òke mimọ́ rẹ?
[2]Ẹniti o nrìn dede, ti nṣiṣẹ ododo, ti o si nsọ otitọ inu rẹ̀.
[3]Ẹniti kò fi ahọn rẹ̀ sọ̀rọ ẹni lẹhin, ti kò si ṣe ibi si ẹnikeji rẹ̀, ti kò si gbà ọ̀rọ ẹ̀gan si ẹnikeji rẹ̀.
[4]Li oju ẹniti enia-kenia di gigàn; ṣugbọn a ma bu ọla fun awọn ti o bẹ̀ru Oluwa. Ẹniti o bura si ibi ara rẹ̀, ti kò si yipada.
[5]Ẹniti kò fi owo rẹ̀ gbà èle, ti kò si gbà owo ẹ̀bẹ si alaiṣẹ. Ẹniti o ba ṣe nkan wọnyi kì yio yẹsẹ lailai.

23/04/2021

ORIN DAFIDI 14:1-7
[1]AṢIWERE wi li ọkàn rẹ̀ pe, Ọlọrun kò si. Nwọn bajẹ, nwọn si nṣe iṣẹ irira, kò si ẹniti nṣe rere.
[2]Oluwa bojuwò lati ọrun wá sara awọn ọmọ enia, lati wò bi ẹnikan wà ti oye ye, ti o si nwá Ọlọrun.
[3]Gbogbo wọn li o si jumọ yà si apakan, nwọn si di elẽri patapata; kò si ẹniti nṣe rere, kò si ẹnikan.
[4]Gbogbo awọn ti nṣiṣẹ ẹ̀ṣẹ kò ha ni ìmọ? awọn ẹniti njẹ enia mi bi ẹni jẹun, nwọn kò si kepè Oluwa.
[5]Nibẹ ni ẹ̀ru bà wọn gidigidi: nitoriti Ọlọrun mbẹ ninu iran olododo.
[6]Ẹnyin dojutì ìmọ awọn talaka, ṣugbọn Oluwa li àbo rẹ̀.
[7]Tani yio fi igbala fun Israeli lati Sioni jade wá! nigbati Oluwa ba mu ikólọ awọn enia rẹ̀ pada bọ̀, Jakobu yio yọ̀, inu Israeli yio si dùn.

Letter Ayo ato e lowo
23/04/2021

Letter Ayo ato e lowo

Anu ma wa e ri ninu osun yi
22/04/2021

Anu ma wa e ri ninu osun yi

Address

Ikosi

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Oro itunu posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share