Olorun Ase Oro C &s Church Agbojesu Conference

Olorun Ase Oro C &s Church Agbojesu Conference A Cherubim and Seraphim Church Olorun Ase Oro Was found and created by Founder Snr.Apostle Prophet E.O Ogedengbe

01/01/2022

Happy 🌠🌠🌠New🌠🌠🌠Year🌠🌠🌠May the Glory of God shine in our lives in Jesus name

Iwo to ba ni igbagbo pe ko si ohun ti ERI o le se.."niwomba osu kan to ku ki ödun yii to pari ..ogo ti aye o lero pe o l...
10/11/2021

Iwo to ba ni igbagbo pe ko si ohun ti ERI o le se.."niwomba osu kan to ku ki ödun yii to pari ..ogo ti aye o lero pe o le sëlë ninu aiye rë,oya ko bërë sini ma sëlë...
E woo,awön kan ti ku Lana, nibi ti awönkan nsukun lôwölowö nibë ni awön kan nki ara wön ku ori ire..Lorukö Jesu,ki odun yii to pari,aiye a ki ë ku ori ire..oo ni sunkun ..Jesu Oluwa wa....

A dupë lowö OlorunTo fi Jesu Kristi fun waLati ra araiye padaLowö èsë ati èsu...    Lorukö Jesu"ni iwomba eyi toku ki öd...
09/11/2021

A dupë lowö Olorun
To fi Jesu Kristi fun wa
Lati ra araiye pada
Lowö èsë ati èsu...
Lorukö Jesu"ni iwomba eyi toku ki ödun yii pari a o ni ku iku oro..ariwo ëgbami ë ba mi gbe ko ni jë ipin emi ati rë..
Ariwo Ayo,ariwo idunu, e wa wo ire tuntun ti Olorun ti se "Lorukö Jesu iru ohun bë ni ko ma fö sinu aiye wa....Wön o ni sinku enikankan laarin wa, atömöde ati agbalagba,,Jesus Oluwa wa....

Hello Everyone😀!!!        Happy New Month!!!🌠🌠⚡  Our Annual ARK OF CONVENANT Anniversary(AJÖDUN ERI🚩ÖLORUN ASE ORO) Is o...
01/09/2021

Hello Everyone😀!!!
Happy New Month!!!🌠🌠⚡
Our Annual ARK OF CONVENANT Anniversary(AJÖDUN ERI🚩ÖLORUN ASE ORO) Is on the 3rd of October ,1st Sunday next month..
The Vigil commence on the 10th of September,this Month and it ends on the 30th while ERI Praise night is on the 1st of October.
EVENT:_@THE ETERNAL SACRED ORDER OF C&S ÖLORUN ASE ORO AGBOJESU CONFERENCE
DATE:ERI Night Vigil start on the 10th, September this Month..
ERI ASE ORO DAY🚩:3-10-2021(Oct. 3)
TIME:Program start by 10:00a.m
VENUE:Back of Baalë House, Awofe Street, Alasia Bus stop, ijoko Sango ota,Ogun State.Nigeria.
Thanks for reading!!!
OBA🚩ERI A GBE WA OOOOO!!!!!!!.....

Mo gbadura fun gbôgbo ëyin ömö ILE-IWE(Students) pata, "Ogo Anu ti iya ati baba yin o ri  lo laiye Lórukō Jësu OBA ERI f...
08/08/2021

Mo gbadura fun gbôgbo ëyin ömö ILE-IWE(Students) pata, "Ogo Anu ti iya ati baba yin o ri lo laiye Lórukō Jësu OBA ERI fi le yin löwö..Exam ti ë ti se tabi eyi ti ë nse löwö Olorun Majëmu a jë kë gbö esi ayo.. Admission to o ti nle lati odun to ti pë iwö ba nigbagbö ninu ÖLORUN ASE ORÖ Lórukō Jësu Admission na ko to yin löwo,Awön Alanu eniyan,Awön Olore gidi ti o ru ëru aiye yin pe ki lë fë ti a dë maa se fun yin Lórukō ERI ASE ORO ko gbeyin pade..e o ni fail,gbôgbo yin pata lë ma se Aseyori nla ti inu awön Obi yin a ma yö so yin...Majëmu Ogo yin losu you ERI ko mu së..Jësu Oluwa wa...

Bi Öjö ba yö,o yö pelu Asë ni..Beeni Oorun ko ni yö ko gbagbe Asë..Mo pa lasë"Lórukō Jësu Ogo abawaye rë yio yö pelu Asë...
12/07/2021

Bi Öjö ba yö,o yö pelu Asë ni..Beeni Oorun ko ni yö ko gbagbe Asë..Mo pa lasë"Lórukō Jësu Ogo abawaye rë yio yö pelu Asë...Jësu Oluwa wa..

Thank God for the successful Alore Anniversary on Sunday 20th June... Lórukō Jësu Ëmimimö Ölorun ò ni dagbéré fun wa...
22/06/2021

Thank God for the successful Alore Anniversary on Sunday 20th June... Lórukō Jësu Ëmimimö Ölorun ò ni dagbéré fun wa...

Iwö to ni igbagbö ni ko se Amin"Ëni to le se örö aye ë,to ma gbe ë de ilu Öba,ibi Ayo,ibi ifökanbalë,ibi ogo, Ani de gbô...
05/06/2021

Iwö to ni igbagbö ni ko se Amin"Ëni to le se örö aye ë,to ma gbe ë de ilu Öba,ibi Ayo,ibi ifökanbalë,ibi ogo, Ani de gbôgbo ibi ire to wun ë ko de,Lórukō Jësu,ÖBA ERI ASE ORO,ERI ÖLÖLA,ko gbeyin pade...

Bi Osu yii ti n pari loni Lórukō Jësu Ogun to da Ogo aiye yin duro lojukan ti ko jë ko föhun, Lórukō Jësu Ogun naa pari ...
31/05/2021

Bi Osu yii ti n pari loni Lórukō Jësu Ogun to da Ogo aiye yin duro lojukan ti ko jë ko föhun, Lórukō Jësu Ogun naa pari loni;mo ni ohun to nba yin ninu jë to tun payin ni ëkun ti ko se sö Lórukō isoro naa pari loni..OBA ERI As'öröd'ayö a payinlërin Ayo...Jësu Oluwa wa..

Mo sö pelu Asë Ipe ti Ölorun fi pe mi; Ogun idile iya ati baba to ni ë o ni gberi, Lórukō Olorun Oba  Eri Ase Örö oya ë ...
09/05/2021

Mo sö pelu Asë Ipe ti Ölorun fi pe mi; Ogun idile iya ati baba to ni ë o ni gberi, Lórukō Olorun Oba Eri Ase Örö oya ë lö fiwön se atëgun wönu ogo lö....

Address

Back Of Baale House Awofe Street Alasia Ijoko Sango Ota
Ijoko

Telephone

+2348032354414

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Olorun Ase Oro C &s Church Agbojesu Conference posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share