01/03/2026
A ku afojuba Osu titun,mo gba ni Adura wipe enikookan wa ti Olorun mu ri ojo oni,ki olukuluku wa maa rin wonu Ogo wa lo loruko Jesu Kristi Oluwa wa.
Gbogbo Eni to nfe itusile kuro lowo aisan ati Emi Aimo ki e maa gba Alafia pipe.Awon to nfe Aanu ki won maa ba Aanu ti ko ni igbiimo pade.
Osu Titun yii yoo fohun Ogo ninu aye enikookan wa,Irin Ajo wa yoo jasi OPE loruko nla Jesu,Amin.
πππππππ