ERI OBA AMONA

ERI OBA AMONA Prayer Mountain

On a hill far and nearThe sound of trumpet Calling you the beloved
02/06/2026

On a hill far and near
The sound of trumpet
Calling you the beloved

25/05/2026
E GB'ori nyin soke enu ona,      K’Oluwa ogo wole     Enit’ O f‘eje re r’aiye pada      O mbo lati gba ‘joba. Hosannah, ...
27/03/2026

E GB'ori nyin soke enu ona,

K’Oluwa ogo wole

Enit’ O f‘eje re r’aiye pada

O mbo lati gba ‘joba.

Hosannah, enyin Orun

Halleluyah, eyin Aiye,

Orun, Osupa, e wole

Kabiyesi, f 'Oba wa.

Awa Iran Israeli ni Afrika

E gb‘ola Oluwa ga

Ajagun -molu Wa ti goke lo

Lati lo pese aye.

Wo, Oba wa ninu Olanla Re,

Gun keke Ofurufu

Agogo Orun pelu korin lyin

‘Ghat’Oba Ogo wole.

Okan mi nfa s‘Agbala ayo na

Nibiti Kristi gunwa

Odi yika ati Agbala Re

Wura l'a fi se loso

Agbara Merinlelogun wole

Pelu ade wura won

At'awon Eda Alaye merin

Nwon nfi iye fo f 'ayo.

Hosannah, enyin Orun

Halleluyah, eyin Aiye,

Orun, Osupa, e wole

Kabiyesi, f 'Oba wa.

Whither, pilgrims, are you going,Going each with staff in hand?We are going on a journey,Going at the King's command,Ove...
11/03/2026

Whither, pilgrims, are you going,
Going each with staff in hand?
We are going on a journey,
Going at the King's command,
Over hills and plains and valleys,
We are going to His palace,
Going to the better land

On this sacred journey
We seek human dignity.
Each one of us is precious.
Show respect and empathy.
WE ARE PILGRIMS OF HOPE.
FOLLOWING THE WAY.
OUR EYES ARE FIXED ON JESUS




Mo n te siwaju lona naMo n goke si lojojumoMo n gbadura bi mo ti n loOluwa jo gbe mi sokeOluwa jo gbe mi sokeFami lo si ...
01/03/2026

Mo n te siwaju lona na
Mo n goke si lojojumo
Mo n gbadura bi mo ti n lo
Oluwa jo gbe mi soke

Oluwa jo gbe mi soke
Fami lo si ibi giga
Apata to ga jumi lo
Oluwa jo gbe mi soke

Ife okan mi ko duro
Larin 'yemeji at'eru
Awon miran le ma gbe'be
Ibi giga lokan mi fe

Mo fe ki nga ju aye lo
Ninu ogo didan julo
Mo ngbadura ki nle de 'be
Oluwa mumi de 'le na.

Fa mi lo si ibi giga
L’aisi Re nko ni le de 'be
Fa mi t**i d’oke orun
Ki nkorin lat'ibi giga.




17/01/2026

IPADE MAJEMU 2026

Address

Ori Oke Adura Eri Oba Amona, Asunle Area Oloko Fefe Victory Estate, Odo Ona Kekere
Ibadan

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when ERI OBA AMONA posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Category