Michael JP

Michael JP Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Michael JP, Church of God, Ibadan, Ibadan Outlying.

EMI oluwa Jehovah nbe Lara mi, mo ko EMI iku ojiji ATI Isa oku patapata, tomotomo, ni Oruko jesu ni mo gbadura. Amin πŸ™‡
25/09/2025

EMI oluwa Jehovah nbe Lara mi, mo ko EMI iku ojiji ATI Isa oku patapata, tomotomo, ni Oruko jesu ni mo gbadura. Amin πŸ™‡

Gbogbo Ogun iponju Lori aye re ati ise re, oluwa ko se wole, ni Oruko jesu kristi Gbogbo Ogun gbese Lori Aya re ati ise ...
23/09/2025

Gbogbo Ogun iponju Lori aye re ati ise re, oluwa ko se wole, ni Oruko jesu kristi
Gbogbo Ogun gbese Lori Aya re ati ise re, olorun ko ISE wole, ni Oruko jesu kristi πŸ™
Gbogbo Ogun ekun Kikoro Lori aye re ATI ise re, olorun ko se wole, ni Oruko jesu kristi πŸ™
Gbogbo Ogun ka jeun laro, ka ma jeun la le, olorun ko se wole, ni Oruko jesu kristi
Ogun aisan ninu Ara, olorun ko se wole, ni Oruko jesu
Ogun ma se aseyori Lori Omo ati Lori ise yin, olorun ko se wole, ni Oruko jesu kristi
Ogun ma ri aanu gba Lori aye Iwo ati Omo re, olorun ko se wole, ni Oruko jesu kristi
Beni yio RI, ko yi pada, jesu oluwa, AminπŸ™πŸ™πŸ™πŸ™

Gbogbo IBI ti o TI Fi enu ko, TI o di ona aanu Ati ojurere mo o, olorun ko Fi Aanu gba yin, ni Oruko jesu kristi πŸ™ πŸ™ πŸ™ G...
23/09/2025

Gbogbo IBI ti o TI Fi enu ko, TI o di ona aanu Ati ojurere mo o, olorun ko Fi Aanu gba yin, ni Oruko jesu kristi πŸ™ πŸ™ πŸ™
Gbogbo IBI ti o ti sise SI oloore, olorun ko Fi Aanu gba yin pade, ni Oruko jesu kristi πŸ™ πŸ™ πŸ™
Gbogbo IBI ti won ti Fi enu ba ti yin JE, aanu oluwa ko tu yin sile, ni Oruko jesu kristi πŸ™ πŸ™
Gbogbo IBI ti a ti ko Yin sile, aanu ko gbe yin jade, ni Oruko jesu kristi πŸ™πŸ™πŸ™πŸ™πŸ™πŸ™

Amin jesu kristi πŸ™
19/09/2025

Amin jesu kristi πŸ™

Owo afinisesi Lara yin Owo ijakule Lara yin Owo ibanuje Lara yin Owo asian Lara yin Owo gbese Lara yin, TI Ogun ajogunb ...
18/09/2025

Owo afinisesi Lara yin
Owo ijakule Lara yin
Owo ibanuje Lara yin
Owo asian Lara yin
Owo gbese Lara yin, TI Ogun ajogunb Fi n ba yin rin irin Ajo, Owo naa gbe danu, loruko jesu kristi
OGUN KI ENIYAN SISE, KO MA NI AKOJO, LORI AYE YIN, OGUN NAA PARE LORI YIN LONIπŸ™‡

18/09/2025

Today Almighty God, by your word, cleanse us from all filth and sustain us in the ways of righteousness. May the ancestral sin and guilt never deprive us of your love and kindness in Jesus Mighty name,πŸ™
Good morning, do have a wonderful and fulfilling day 🌹πŸ₯°β€οΈ

AMEN πŸ™πŸ™πŸ™
17/09/2025

AMEN πŸ™πŸ™πŸ™

LORU ONI, Ina πŸ”₯ Omo Koni Jo o, ni loruko jesu kristi πŸ™OFA IKU KONI WOLE SI OMO RE LARE, NI ORUKO JESU KRISTI πŸ™
14/09/2025

LORU ONI, Ina πŸ”₯ Omo Koni Jo o, ni loruko jesu kristi πŸ™
OFA IKU KONI WOLE SI OMO RE LARE, NI ORUKO JESU KRISTI πŸ™

Address

Ibadan
Ibadan Outlying

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Michael JP posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Category