06/10/2024
E gbo mi bayi mo n sotele si inu aye enikan ti on wo mi lowo yi, wipe itan aye re ti oti pe maa jasi ayo ninu osu kewa odun yi, pelu ipe i fi amii ororo Yan,ni oruko Jesu ni mo wi,wa ri ogo lo laye, gbogbo eni bani ki omoo ri ogo lo di eni agbegbin ni oruko Jesu oluwa wa, Amin.