01/02/2026
Sunday School: 1/2/26
OLORUN IDAWOLE: John Cha 8 vs 1-11
Isaiah 59:1-2: Nitooto apa oluwa ko kuru ju lati gbani, beni eti re ko wuwo ti ki yio fi gbo. Sugbon awon aisedede nyin to ya nyin kuro lodo olorun nyin, awon ese nyin to pa oju re mo kuru lodo nyin, beni ki yio gbo.