27/05/2026
Psalms 127:3-5
[3]Kiyesi i, awọn ọmọ ni ini Oluwa: ọmọ inu si li ère rẹ̀.
Lo, children are an heritage of the LORD: and the fruit of the womb is his reward.
[4]Bi ọfà ti ri li ọwọ alagbara, bẹ̃li awọn ọmọ igbà èwe rẹ.
As arrows are in the hand of a mighty man; so are children of the youth.
[5]Ibukún ni fun ọkunrin na ti apo rẹ̀ kún fun wọn: oju kì yio tì wọn, ṣugbọn nwọn o ṣẹgun awọn ọta li ẹnu ọ̀na.
Happy is the man that hath his quiver full of them: they shall not be ashamed, but they shall speak with the enemies in the gate.
Happy Children's Day to Celestial children worldwide, and happy juvenile harvest in advance.
Mummy, Daddy, we are grateful for your sacrifices on us.
We say thank you for all you do.
May the good God of Celestial Church bless you, and protect our children. Amen
fans
CCC Cardoso YOUTH FORUM
Following