22/03/2026
Proverbs 14:23-25
[23]Ninu gbogbo lãla li ère pupọ wà: ṣugbọn ọ̀rọ-ẹnu, lasan ni.
In all labour there is profit: but the talk of the lips tendeth only to penury.
[24]Adé awọn ọlọgbọ́n li ọrọ̀ wọn: ṣugbọn iwère awọn aṣiwère ni wère.
The crown of the wise is their riches: but the foolishness of fools is folly.
[25]Olõtọ ẹlẹri gbà ọkàn silẹ: ṣugbọn ẹlẹri ẹ̀tan sọ̀rọ eke.
A true witness delivereth souls: but a deceitful witness speaketh lies.