Ohun Oluwa ti san ara Apostolic Church

Ohun Oluwa ti san ara Apostolic Church Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Ohun Oluwa ti san ara Apostolic Church, Religious organisation, Lane 3, Oluwatedo behind TACN, Basiri, Ado-Ekiti.

24/04/2026
15/03/2026

Eyin eniyan olorun, Mo ki yin loruko Jesu Kristi Oluwa wipe a ku isinmi oni o. Bi Oluwa ba fa bibo re seyin ni ose to nbo, emi wa ase pupo re laye.
Gege bi a se n gbe atejise wa jade ni nkan bi ojo die seyin. Oni ni o pe ojo keje ti a o ma soro lori ise ti olorun ni ki nba awon Oloro so ni orile ede yii ati ni gbogbo agbaye.
Nitori naa, e faaye sile lati wo fonran yi.

12/03/2026
08/03/2026

Oro ti Oluwa bami so nipa orile ede la'gbaye, paapa julo si awon Oloro. Video yi je eyi ti o ko gbodo ma wo

  CAC GENERAL EVANGELISTS FROM 1943 TILL DATEApostle Joseph Ayo Babalola1st General Evangelist(1943 – 1959)Prophet D. O....
07/03/2026



CAC GENERAL EVANGELISTS FROM 1943 TILL DATE

Apostle Joseph Ayo Babalola
1st General Evangelist
(1943 – 1959)

Prophet D. O. Babajide
2nd General Evangelist
(1959 – 1991)

Evangelist J. O. Alokan
3rd General Evangelist
(1993 – 2006)

Prophet S. K. Abiara
4th General Evangelist
(2007 – 2017)

Prophet Hezekiah Oluboye Oladeji
2018 till date

06/03/2026

Another day to behold God's faithfulness. Mo ki yin loruko Jesu Kristi Oluwa wa wipe a ku a foju ba osu keta ninu odun yi. A n tesiwaju ninu Oro ti Oluwa ba wa so nipa orile ede gbogbo. Abala yi je apa keerin (part 4). Mo ro wa, e je ka farabale gbo.

06/03/2026

I have not been able to continue the work God has send me to deliver to countries of the world. I sincerely apologize. I will post the part 4 today and continue from there by His grace. So endeavour to watch it and most importantly share it, like it and comment 👍💯

Address

Lane 3, Oluwatedo Behind TACN, Basiri
Ado-Ekiti

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ohun Oluwa ti san ara Apostolic Church posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share