Agbala Awon Amoye

Agbala Awon Amoye Official Page of AGBALA AWON AMOYE. Led by Wòlí Àmòye Agba. Prophetic guidance, spiritual teachings, herbal wisdom, books, consultations, and updates.

Send a message for inquiries. 📞 AMOYE AGBA-- 07088515807

06/08/2026

ANBE OLOHUN OMO BIBI

egbo ailu, egbo jokoje, ewe koyin sorun, obi ajopa tikobo lara, ao jo won papo, obinrin ye amafi foko tutu mu, lehin to pari nkan osu re odaju

06/08/2026

ANBE OLOHUN OMO BIBI

obi ajopa eyiti koni apa lara rara, ao jo pelu oko atare kan, ao mafi mafi foko tutu mu awa pelu oko wa odaju

06/08/2026

BI OYUN BANYA LARA ALABOYUN, IGBE OYUN KO SOKE

ewe jenjoko mesan, eyo atare mesan, ao fi ewe kan lele, ao fi eyo atare kan si, ao tun fi ewe kan le lori, ao tun fi eyo atare kan si, bi ao se to telerawon ti mesesan fima pe niye, ao we ni owu funfun ati dudu, ao wa fi wo obinrin ye ni isale inu re wa soke, ao wa so ko soke, odigba ti osu re bape kato ja kuro odaju

06/08/2026

IGBE OYUN KO SOKE

idon obinrin Ewe jenjoko mesan, eyo atare mesan, ye ni ao tito telerawon, ao wa we ni owu funfun ati dudu, ao soko soke, odi igba ti osu re bape kato ja.

06/08/2026

EDA OBINRIN

Obi ajopa ti kobo lara, obi funfun kan, obi pupa kan, ao jo ma odidi atare kan, ati ifun inu tagiri kan, ao jo papo, ao mafi foko tutu mu

02/08/2026

HAPPY FIRST SUNDAY OF THE MONTH

01/08/2026

ONA ABAYO FUN AWON TI PARIWO KOSI OWO

Elo wa ewe imi eesu,a o lo oelu epo obo
A o gun no ose
A o bu die sori apoti a o te ni ejiogbe
A o bu die sori kankan a o te ni ejiigbe
A o wa joko Lori apoti yi,a o ma we osena pelu adura pe ti abajoko le apoti dandan ni kadide
Gbogbo enijoko le atila,atilowo mi lol oya edide...
Tabawe tan a o si tori apoti danu
Emeta lao we lera
Odaju

01/08/2026

EBE AGBA TODAJU PUPO
Obi ipa, eso agogogun, ao gun pomo ose dudu, ao kosi ori ilele lasan ninule, ao ma buwe, ise yara tuni sile lodo awon agba, ti ona oore yio si taara.

01/08/2026

FUN ORI FIFO TIKO LO
Ewe ogbe ori akuko a o SE lagbo,a o Fi ewe Taho eko kuro ninu e SE kankan ,a o Fi ose si fo ori na pelu agbo na
Fun inarun_-:a o Fi agbo na we ni

01/08/2026

APORO, APARUN GBOGBONISE
Ewe apawo, ose dudu, ao gun papo, ao ko sinu iwo malu, ao soko, ao ma po diedie sinu omi fun eni tobani eyikeyi arun inu.

Address

Ado-Ekiti

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Agbala Awon Amoye posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share