21/01/2026
*NEW GENERATION PRAYER MOUNTAIN UNSEARCHABLE POWER OF GOD
ELL-BETHEL. Welcome you to morning prayer
21th of January 2026
π Ministering :- APOSTELI M QUADRI
π― NITORI AANU NI MOFE KINSE EBO"
*Text:-HOSEA:6v6'
*God bless as you listen and share in thy mighty name of Jesus Chris amen π
For :- *PRAYERS* & *COUNSELING*
Call:- 08038271455, 09126556903..
[Nitori a ko wipe Emi yio se oore ofe fun eniti Emi o se oore ofe, Emi yio sanu eniti Emi yio sanu fun, nitorina ninu ijade ati iwole re wa ri Aanu gba, nidi okowo re, nibi ise re, anu yio wao ri wa di alabukun fun gbogbo ogo yio si maa je ti OLORUN. ma gbagbe o oni ni ojo Isin fun awon alaseyori Lori oke ELL-BETHEL ni olujobi town lati de Koboro ni itori lona Abeokuta JESU ndoru de o lati ago mesan aro si ago Kan osan eni ni ojo Ayo re.