ABK Greenpasture Land & Homes Ltd.

Website

ABK Greenpasture Land & Homes Ltd. Greenpasture Homes: building
affordable housing for all..

20/10/2026
Spiritual spouse in relationship with human beings. evil companion.
16/10/2026

Spiritual spouse in relationship with human beings. evil companion.

KINI ANPENI ỌKỌ ỌRUN ATI AYA Ọ̀RÚN?

Ọkọ̀ ọrùn je alijanu buruku ti oma ba obinrin wa si aiye lati ma wa da la mu ni aiye, ni tori pe oni majemu tiwon tida funrawon lati ode orun..
Majemu tiwa larin awon mejeji pe awon koni ya arawon, awon oko orun ti anso yi ama ni majemu pe ti obinrin yi bawa si aiye kogbodo ni oko miran ma, besini okunrin inu won na kogbodo fe iyawo miran, idi niyi tofi jepe opolopo won okin ri oko tabi aya fe lasiko, tori awon Oko orun ati aya orun yi koni jeki o ri ololufe miran leyin ohun..
Kosi nkan Toma nfa gbogbo eleyi ju majemu toti wa larin won lati ode orun koto wasi aiye gegebi eniyan..

Opolopo won tun tise igbeyawo ni ode orun ki won to wasi aiye, awon elomiran gan ti bi Omo ni nu won ohun na ni yio fa tojepe ti elomiran ba de ile babalawo won ma so fun pe oti bi Omo kan si ibi kan ti ohun ko si ni mo pe ohun ti bi Omo si ibi kan.
be na si okunrin, awon na onima pe awon tise isemi kan ni ibi kan ki won to wa si aiye, awon omo elegbe ni won ma saba ni oko orun to ri pe awon ni ape ni aje orun , tiwon tilo isemi kan tele ni ibi kan ki won to wa si ile aiye ..
ti won bawa si ile aiye awon egbe won yio tele won wasi ile aiye .
nkan ti afi pe won ni omo elegbe ni yen, ninu awon ti won ba ni oko tabi aya ninu won ma tele won wa si ile aiye tori majemu toti wa larin lati ode orun.

BI ASE NDA ENITI OBANI OKO ORUN ATI AYA ORUN


TIo ba la ala pe onma ni lpalopo no oju orun

Alijanu yen lo wa ba ni asepo ni oju orun... Eleyi tumosi pe oni tohun ko ni tete ri oko tabi aya, gbogbo igba toba ti gbe igbese pe ohun fe ni oko tabi iyawo... koni ri oju ture ma
awon alijanu buruku yen ni won daru latara ipalopo.. ki oni tohun murasi adura dada.

KI OWU JAKAWO MAKO ÈNÌYÀN NI GBOGBO IGBA

ijakule yio ma sele si ni gbogbo igba ni ibi ise

Ki oni tohun mura si adura ati ise igbinyanju daadaa kio le ba ri nkan rere gbese laye tori emi buruku ni ki ni je.

OGUN KI SISE NI ARA WỌN

TI won ba sise igbinyanju fun won ko ni sise ni ara won afi eto adura ati sara ni yio ma sise fun won tori awon alijanu yii oma ba ogun yen je mo lara.

NKAN KO NI LODEDE FUN WON BIKI OMARI PROMISE AND FAIL

Nkan ko ni lo dede larin loko laya,bi ki ija ma sele larin won tabi ki won ma ko rira ara won tabi aini owo lowo, kosi bi won sele ma gbinyanju to koni bosi

se iwadi arare dada kiole ma ona abayo si isoro aiye re.. tori nkan ti oni agbara pupo ni oko orun ati aye orun je.
Adura ati ise igbinyanju gidi lama fin segun emi buruku yi..

FUN IWADI NIPA IRAWO ATI AKOSEJAIYE RE....follow page yi.

15/10/2026

a great opportunity for Ogun and Lagos state residential. Federal Housing Authority Homes provision. visit our office at Jeunbioba building Olorunsogo Moshood Abiola Way Abeokuta Ogun State. 0810 034 7157
GreenPasture Homes Greenpasturehomes
Damilare Oloyede

09/10/2026

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Popoola Wasiu, Francis Oluwole Akinwunmi, Henry Taiwo Oyeboade, Oladele Gideon, Kehinde Oluwabukunolami, Solomon Ezenwa, Samuel Soremekun, Adeniyi Egin, Ayobami Monday, Abdul Azim Ibn Tajudeen, Yinusa Oseni Kayode, Akorede Halleluyah Morawo, Jeremiah Inioluwa, Oyedele Rodiyat, Thomas Adesola, Dada Adeyemi, Taiwo Afolabi, Kehinde Ibrahim, Taiye Olanrewaju Emmanuel, Folashade Oyetola, Iyanuoluwa Fadare Disu, Akano John Oluwatosin, Woli Ase Oro, Adeboye Clement, Anone Omachi, Mardoche Lecosta Kabanga, Paul Ayeni, Kehinde Joseph Ajayi, Michael Ofedegbe

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Popoola Wasiu, Francis Oluwole Akinwunmi, Henry Taiwo Oye...
07/10/2026

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Popoola Wasiu, Francis Oluwole Akinwunmi, Henry Taiwo Oyeboade, Oladele Gideon, Kehinde Oluwabukunolami, Solomon Ezenwa, Samuel Soremekun, Adeniyi Egin, Ayobami Monday, Abdul Azim Ibn Tajudeen, Yinusa Oseni Kayode, Akorede Halleluyah Morawo, Jeremiah Inioluwa, Oyedele Rodiyat, Thomas Adesola, Dada Adeyemi, Taiwo Afolabi, Kehinde Ibrahim, Taiye Olanrewaju Emmanuel, Folashade Oyetola, Iyanuoluwa Fadare Disu, Akano John Oluwatosin, Woli Ase Oro, Adeboye Clement, Anone Omachi, Mardoche Lecosta Kabanga, Paul Ayeni, Kehinde Joseph Ajayi, Michael Ofedegbe

Address

Jeun Bi Oba Building Olorunsogo Abiola Way Abe
Obada
112106

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when ABK Greenpasture Land & Homes Ltd. posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share